Iya Gbonkan
Margaret Bandele Olayinka (tí a bí ní ọjọ́ ẹ̀rìn-lé-lẹ́wàá oṣù kẹsán ọdún 1958), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ìyá Gbónkán, jẹ́ òṣèré òníwòsàn ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà, tí ó jẹ́ olókìkí púpọ̀ jùlọ fún ìrísí ojú ẹ̀rù rẹ̀.
Iṣẹ́ Rẹ̀
àtúnṣeÌyá Gbónkán sábà máa ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí àjẹ́ búburú ní eré jara ti Yorùbá, èyí fi hàn gedegbe nípasẹ̀ ìrírí rẹ̀. Ní ìbẹ̀rẹ̀ 70s ni ó jẹ́ ẹni mímọ̀ olókìkí nígbà tí ó ṣe àfihàn ní jara Pa Yemi Elebu'bon láti ọwọ́ Ifá Olókùn àti ní Olórí Èmèrè àti ní Kòtò Ọ̀run tí Yekinni Ajileye ṣe.[1]
Àwọn Ìtọ́ka Sí
àtúnṣe- ↑ Olukomaiya, Funmilola (28 February 2020). "10 Nollywood Villains You Must Know". P.M. News. Retrieved 8 July 2022.