Iyipada oju-ọjọ ni Amẹrika
Ìyípadà ojú-ọjọ́ ti yọrí sí ìgbọ́ná ní America pẹ̀lú 2.6 °F (1.4 °C) láti ọdún 1970. [2] Ojú-ọjọ́ ti America ń yípadà lọ́tà tó yàtọ̀ sí ti àwọn agbègbè rẹ̀.[3][4] Láti ọdún 2010 sí ọdún 2019 ni ìlú America ti ń ní àdojúkọ ìgbóná nínú ojú-ọjọ́.[5]
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ojú-ọjọ́ tó ga jù, àwọn ẹranko tó ti ń lọ sóko ìgbàgbé, àgbàrá òjò àti ìyuàngbẹ-ilẹ̀ ń pọ̀ si.[6][7][8] Àwọn ìyípadà tó ń dé bá ojú-ọjọ́ ń kó ipa ribiribi lórí àwọn ìjì-líle àti ìpele òkun tó ń ga si, ó sì tún ń kan àwọn agbègbè nínú ìlú.
Ní àpapọ̀, láti ọdún 1850, orílẹ̀-èdè America ti tú èéfín gáàsì tó pọ̀ jù lọ, ju gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tó ń lo gáàsì, tó sì ń ní ìyípadà tó ń dé bá ojú-ọjọ́ wọn.[9][10]
Eefin gaasi itujade
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Empty citation (help) (Direct link to graphic; archive)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ "Sixth Assessment Report". www.ipcc.ch. Retrieved 2021-08-20.
- ↑ Heidari, Hadi; Arabi, Mazdak; Warziniack, Travis; Kao, Shih-Chieh (2020). "Assessing Shifts in Regional Hydroclimatic Conditions of U.S. River Basins in Response to Climate Change over the 21st Century" (in en). Earth's Future 8 (10): e2020EF001657. Bibcode 2020EaFut...801657H. doi:10.1029/2020EF001657. ISSN 2328-4277. https://agupubs.onlinelibrary.wiley.com/doi/abs/10.1029/2020EF001657.
- ↑ US EPA, OAR (2016-06-27). "Climate Change Indicators: U.S. and Global Temperature". www.epa.gov (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-20.
- ↑ Heidari, Hadi; Arabi, Mazdak; Ghanbari, Mahshid; Warziniack, Travis (June 2020). "A Probabilistic Approach for Characterization of Sub-Annual Socioeconomic Drought Intensity-Duration-Frequency (IDF) Relationships in a Changing Environment" (in en). Water 12 (6): 1522. doi:10.3390/w12061522.
- ↑ US EPA, OAR (2015-11-06). "Climate Change Indicators in the United States". www.epa.gov (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29.
- ↑ Casagr, Tina (2022-02-16). "Climate Change and Invasive Species - NISAW" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-29.
- ↑ US EPA, OAR (2016-06-27). "Climate Change Indicators: U.S. and Global Temperature". www.epa.gov (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-20.
- ↑ Empty citation (help)