Izu Ojukwu
Izu Ojukwu jẹ́ olùdarí fíìmù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ní ọdún 2007, ó gba àmì-ẹ̀yẹ fún ìsọ̀rí Olùdarí tó dára jù lọ fún fíìmù Sitanda, ní àyẹyẹ ọlọ́dún kẹta ti Africa Movie Academu Award. Àmì-ẹ̀yẹ mẹ́sàn-án ni wọ́n yàn án fún, àmọ́ ó márùn-ún ló gbà níbi ayẹyẹ náà.[1][2]
Izu Ojukwu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Jos, Nigeria |
Iṣẹ́ | Director |
Filmography ti a yan (gẹgẹbi oludari)
àtúnṣe- Amina (2021)
- Power of One (2018)
- 76 (2016)
- Alero's Symphony (2010)
- The Child (2009)
- Nnenda (2009)
- Distance Between (2008)
- Cindy's Note (2008)
- White Waters (2007)
- Laviva (2007)
- Sitanda (2006)
- 3rd Africa Movie Academy Awards 2007 fun Oludari Dara julọ [3]
- GL 1 & 2 (2005)
- Across the Niger (2003)
- Moving Train (2003)
- Battle of Love(2003)
- Desperadoes 1 & 2 (2001)
- Eleventh Hour(2001)
- Love Boat (2001)
- The World is Mine (2001)
- Showdown(2000)
- Iva (1999)
- Icabod (1993)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Coker, Onikepo (4 May 2007). "Africa Celebrates Film Industry at AMAA 2007". Mshale Newspaper (Minneapolis, USA: Mshale Communications). Archived from the original on 3 March 2012. https://web.archive.org/web/20120303204433/http://www.mshale.com/article.cfm?articleID=1407.
- ↑ "AMAA Nominees and Winners 2007". African Film Academy. Retrieved 14 September 2010. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Coker, Onikepo (4 May 2007). "Africa Celebrates Film Industry at AMAA 2007". Mshale Newspaper (Minneapolis, USA: Mshale Communications). Archived from the original on 3 March 2012. https://web.archive.org/web/20120303204433/http://www.mshale.com/article.cfm?articleID=1407.