Jaja ìlú Òpóbò

(Àtúnjúwe láti Jàjá ìlú Òpobò)

Ọba Jaja Ìlú Opobo (Orúkọ Àbísọ: Jubo Jubogha; 1821–1891) jẹ́ Ọba akọkọ ìlú Òpóbò tí wọn ń pé ní Amanyanabo.[citation needed] Òun ni Olúdàsìlè Òpóbò tí ó wà ní ìpínlè Rivers ní orílé èdè Nàìjíríà.[citation needed] Wọ́n bi sí Umuduruoha Amaigbo, ibi tí a mọ̀ sí Ìpínlẹ̀ Imo lóde òní, ọjọ ìbí rẹ̀ àti àwọn òbí rẹ á kò mọ.

Ọba Jaja ti OPOBO
Jaja ìlú Òpóbò
Coronation 25 December 1870
Predecessor Ibani
Successor Ubani
Born c. 1821
Burial Opobo

Jaja gbà ìyàǹda lọ́wọ ọgá rẹ ní ẹnu iṣẹ àti bí ọmọ ọdọ lẹyìn tí ó tí wá lẹnu iṣẹ náà fún ọdún tí ó tí pé. Nígbà tí Ọgá rẹ̀ fẹ́ ṣe aláìsí, ó gba àṣẹ láti lè máa darí okòwò, lẹyìn tí ó sí darí ilé owò tí wọn ń pé ní Anna Pepple House ní agbègbè kàn ní Ninu island [citation needed] Lábẹ́ rẹ ní Anna Pepple gbà àwọn ilé tí wọn tí ń ṣòwò títí tí ìjà fí wà láàrin wọn àti Manilla Pepple tí Ọkọ jumbo darí wọn sọ fún Jaja pé kí bo kúrò ní ìlú Òpóbò (mile mẹ́ríǹlógùn) ní ọdún 1869.[1]

Òpóbò dì Olókòwò tí ó gbajúgbajà ní òwò epo. Jaja gbà ìyàǹda láti ọwó awọn èèbó àti àwọn aláwọ̀ dúdú láti lè tá epo, ní ọdún 1879 ní ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ta Ẹgbẹ̀rún méjọ èpo fún àwọn Èèbó Aláwò funfun. [citation needed]Opobo also shipped palm oil directly to Liverpool. Bí ó tí lẹ jépé òun àti àwon òyìnbó aláwọ̀ funfun ní ááwọ̀, Jaja rí pé àwọn ọmọ rẹ lọ ilé ìwé láti kẹkọọ ní Glasgow, tí ó sí gbà àwọn èèbó láti ṣiṣẹ́ ní ilé ẹkọ kekere ti ó í sí Òpóbò. Ọ sí ṣe ìdínàmọ́ àwọn èèbó tí wọn ń kéde ìhìn rere lati má wọ Òpóbò.[2]

Ní ọdún 1884, Ìpérò ní orílé èdè Berlin, àwọn ará ìlú Yóòrópò sopé Òpóbò jẹ àgbẹgbẹ̀ Awọn èèbó. Nígbà tí Jaja kọọ̀ láti dópin owó orí lọ́wọ awọn èèbó tí wọn ń ṣòwò, igbákejì Consul pé Jaja láti dúndúńrà ni 1887. Wọn gbé Jaja nígbà tí ó bá Ọkọ Èébì kan wọ̀lú ; èyí tí ó gbìyànjú ní Accra ní Gold Coast agbegbe awọn èèbó tí wọn ń pé ní Ghana, tí ó gbéra, tí ó sí Kọ́kọ́ wọ ìlú Lọ́ńdọ̀ọ̀nù tí ó wọ Saint Vincent àti Barbados ní British West Indies[3][4] Ó dé West Indies ni wọn fẹ̀sùn kàn pé ọ dáa rògbòdìyàn sílẹ láàrin àwọn aláwọ̀ dúdú tí ó wà níbè, èyí tí wọn sì ń bínú sí bó tí ṣe ń darí àwọn aláwọ̀ dúdú ní Òpóbò, èyí tí òsì àti ìyàà ń jẹ awọn aláwọ̀ dúdú.[5]

Ní ọdún 1892, wọ́n fún Jaja ní Ìyàǹda láti padà sí ìlú Òpóbò, sùgbón ó di aláìsí nígbà tí wọn ń bi wá sílẹ.[6] Lẹyìn ìgbà lọ ìlú èèbó àti bí ó tí pàdánù ẹ̀mi rẹ ní agbára àti pàṣẹ rẹ̀ tí ń dínkù. [7] Ní ọdún 1903, wọ́n gbé ère kàn kí wọn má ṣe gbàgbé Ọba Jaja ìlú Òpóbò ni Àárín Ìlú Òpóbò.

Àwọn itọkasi

àtúnṣe

Ìkọ ṣile

àtúnṣe
  1. "Jaja of Opobo: The Slave Boy Who Became King". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-25. Retrieved 2022-08-26. 
  2. Zuckerman 2021, p. 37.
  3. Àdàkọ:Cite hansard
  4. Cookey 2005, p. 159.
  5. Adebowale 2019.
  6. Encyclopedia of World Biography, p. 203.
  7. "Jaja of Opobo: The Slave Boy Who Became King". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-25. Retrieved 2022-08-29. 
àtúnṣe

Àdàkọ:Authority control