Jáwó tàbí Ìgbànú jẹ́ àpò ìpawó sí tí àwọn ìyá-lọ́jà àti bàbá-lọ́jà ma ń so mọ́ inú tí wọn yóò daṣọ bo lásìkò tí wọ́n bá ń tajà lọ́wọ́. [1]