Jẹ̀dí jẹ̀dí, tí a tún mọ̀ sí Ìròbo, jẹ́ àìsàn tí ní ṣe pẹ̀lú iṣan pàá pàá jùlọ iṣan inu ihò ìdí.[1][2] ní ibẹ̀rẹ̀, jẹ̀dí ma ń fa kí ènìyàn ó Ma rígbẹ̀ẹ́ yà tàbí kí ó ma yàgbẹ́ gbuuru ní kòṣẹ kòṣẹ.[3]. Tí àìsàn yí bá ti dàgbà tàbí gbó sí ènìyàn lára ni ó ma ń jẹ́ kí ihò ìdí [swelling (medical)|wú]] tàbí pọ́n bí ẹ̀jẹ̀; tí yóò sì ma ye síta bí ìgbà tí ènìyàn ń ṣègbọ̀sẹ̀. Ipò tí ihò ìdí wà yí ni àwọn onímọ̀ọ̀ ìṣègùn òyìnbó ń pe ní "hemorrhoid", nígbà yí ni àìsàn yí tó di àrùn. Tí Ìròbo bá yọ sínú, eléyí lè má mú ìnira bá aláìsàn náà rárá. Amọ́, ìdí rẹ̀ yóò ma ṣẹ̀jẹ̀ síta nígbà tí ó bá ńnṣe ìgbọ̀nsẹ̀. [4] Tí Ìròbo bá yọ síta, ó sábà ma ń mú ìnira dáni lọ́pọ́ ìgbà ní ẹnu ihò ìdí, ẹ̀jẹ̀ tí yóò sìma dà jáde níbẹ̀ yóò dúdú níye.

Ohun tí ó ń fàá

àtúnṣe

Àwọn onímọ̀ kò ì tíì fìdí ohun tí ó ń fa àìsàn jẹ̀dí múlẹ̀ ní pàtó. Àmọ́, ó ṣe é ṣe kí ó jẹ́ pé àwọn ohun tí ó lè ma ṣokùnfà inú gbígbóná tàbí inú rírun ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun tí ó ń fa jẹ̀dí.[5] [6] [7].[8]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Chen, Herbert (2010). Illustrative Handbook of General Surgery. Berlin: Springer. p. 217. ISBN 978-1-84882-088-3. 
  2. Schubert, MC; Sridhar, S; Schade, RR; Wexner, SD (July 2009). "What every gastroenterologist needs to know about common anorectal disorders". World J Gastroenterol 15 (26): 3201–09. doi:10.3748/wjg.15.3201. ISSN 1007-9327. PMC 2710774. PMID 19598294. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=2710774. 
  3. Beck, David E. (2011). The ASCRS textbook of colon and rectal surgery (2nd ed.). New York: Springer. p. 175. ISBN 978-1-4419-1581-8. Archived from the original on 2014-12-30. https://web.archive.org/web/20141230143156/https://books.google.ca/books?id=DhQ1A35E8jwC&pg=PA174. 
  4. "Hemorrhoids". National Institute of Diabetes and Digestive and Kidney Diseases. November 2013. Archived from the original on 26 January 2016. Retrieved 15 February 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Hollingshead, JR; Phillips, RK (January 2016). "Haemorrhoids: modern diagnosis and treatment.". Postgraduate Medical Journal 92 (1083): 4–8. doi:10.1136/postgradmedj-2015-133328. PMID 26561592. 
  6. Rivadeneira, DE; Steele, SR; Ternent, C; Chalasani, S; Buie, WD; Rafferty, JL; Standards Practice Task Force of The American Society of Colon and Rectal Surgeons (September 2011). "Practice parameters for the management of hemorrhoids (revised 2010)". Diseases of the Colon and Rectum 54 (9): 1059–64. doi:10.1097/DCR.0b013e318225513d. PMID 21825884. https://semanticscholar.org/paper/54a9c3802fbdebcb7dd0d8fa432ba4c6fb4904e3. 
  7. Lorenzo-Rivero, S (August 2009). "Hemorrhoids: diagnosis and current management". Am Surg 75 (8): 635–42. PMID 19725283. 
  8. Kaidar-Person, O; Person, B; Wexner, SD (January 2007). "Hemorrhoidal disease: A comprehensive review". Journal of the American College of Surgeons 204 (1): 102–17. doi:10.1016/j.jamcollsurg.2006.08.022. PMID 17189119. Archived from the original on 2012-09-22. https://web.archive.org/web/20120922155502/http://www.siumed.edu/surgery/clerkship/colorectal_pdfs/Hemmorhoids_review.pdf.