J. J. Thomson
(Àtúnjúwe láti J.J. Thomson)
Sir Joseph John "J. J." Thomson, OM, FRS (18 December 1856 – 30 August 1940) je ara Britani asefisiksi ati elebun Nobel. O gbajumo fun iwari elektronu ati awon agbaayekanna, ati fun ida osuwoninale akojo. Thomson gba 1906 Ebun Nobel ninu Fisiksi ni 1906 fun iwari elektronu ati fun ise re lori igbasinu iseitanna ninu awon efuufu.
J. J. Thomson | |
---|---|
Ìbí | 18 December 1856 Cheetham Hill, Manchester, UK |
Aláìsí | 30 August 1940 Cambridge, UK | (ọmọ ọdún 83)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | British |
Pápá | Physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Cambridge University |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Manchester University of Cambridge |
Academic advisors | John Strutt (Rayleigh) Edward John Routh |
Notable students | Charles Glover Barkla Charles T. R. Wilson Ernest Rutherford Francis William Aston John Townsend J. Robert Oppenheimer Owen Richardson William Henry Bragg H. Stanley Allen John Zeleny Daniel Frost Comstock Max Born T. H. Laby Paul Langevin Balthasar van der Pol Geoffrey Ingram Taylor |
Ó gbajúmọ̀ fún | Plum pudding model Discovery of electron Discovery of isotopes Mass spectrometer invention First m/e measurement Proposed first waveguide Thomson scattering Thomson problem Coining term 'delta ray' Coining term 'epsilon radiation' Thomson (unit) |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize for Physics (1906) |
Religious stance | Anglican |
Signature | |
Notes Thomson is the father of Nobel laureate George Paget Thomson. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |