Johannes Hans Daniel Jensen

(Àtúnjúwe láti J. Hans D. Jensen)

Johannes Hans Daniel Jensen (June 25, 1907 ni Hamburg – February 11, 1973 ni Heidelberg) je ara Jemani to je onimo fisiksi inuatomu. Nigba Ogun Agbaye Keji, o sise lori ise okun inuatomu fun Jemani, to unje Agbo Uraniom, ninu ibi to ti se afikun pataki si ipinya awon isotopu uraniom. Leyin ti ogun pari, o sise bi ojogbon ni Yunifasiti ilu Heidelberg. O tun je ojogbon alejo ni Yunifasiti Wisconsin–Madison, the Institute for Advanced Study, Indiana University, ati the California Institute of Technology. Jensen pin Ebun Nobel ninu Fisiksi odun 1963 pelu Maria Göppert-Mayer fun aba won fun afijuwe igbaeyin inuatomu.

Johannes Hans Daniel Jensen
Ìbí25 Osu Kefa, 1907
Hamburg
Aláìsí11 Osu Keji, 1973
Heidelberg
Ọmọ orílẹ̀-èdèara Jemani
Pápáfisiksi
Ibi ẹ̀kọ́Yunifasiti ilu Hamburg
Doctoral advisorWilhelm Lenz
Doctoral studentsHans-Arwed Weidenmüller
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síEbun Nobel ninu Fisiksi (1963)