Ja'afar Abubakar Magaji

Ja'afar Abubakar Magaji je olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà . O n ṣiṣẹ lọwọlọwọ gẹgẹbi ọmọ ẹgbẹ ti o n sójú Mubi North/Mubi South/ Maiha ni Ilé ìgbìmò Aṣoju so fín [1]

Ja'afar Abubakar Magaji
Member of the
House of Representatives of Nigeria
from Adamawa
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
June 2023
ConstituencyMubi North/Mubi South/Maiha
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí4 October 1980
AráàlúNigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress

Igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ

àtúnṣe

Ọjọ́ kẹrin osù kẹwàá ọdún 1980 ni wọn bi Ja'afar Abubakar Magaji, o si gbà oyè BSc. Ẹ̀kọ́ nípa kárakata.

Awọn itọkasi

àtúnṣe