Shiekh Ja'afar Mahmud Adam (tí wọ́n bí ní February 12, 1960 tí ó sì kú ní April 13, 2007) jẹ́ onímọ̀ Islam àti ọmọ-ẹgbé al-Salafiya, tí ó sì tún jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ Jama’at Izalat al Bid’a Wa Iqamat as Sunna ní Nàìjíríà, èyí tí ó jẹ́ ẹgbẹ́ ajẹmẹ́sìn-jẹmọ́-òṣèlú, tó ní olú-ẹ̀ká ní Abuja. Ó gbé ní Kano, ó sì lọ sí Maiduguri fún ọdún Tafsir Ramadan ọdọọdún.[1][2]

Ikú rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n pa Sheikh Ja'afar sínú Mọ́ṣáláṣí rẹ̀ lásìkò àdúrà Subh ní apá North ní Kano ní April 2007.[3][4] Àwọn kan sọ pẹ́ àwọn Boko Haram ló pa á, bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn kan sọ pé Mr. Shekarau, tó jẹ́ gómìnà ìpínlè Kano nígbà náà ló pa á.[5]

Abu Musab Al-Barnawi tó jẹ́ ọmọ Mohammed Yusuf, tó ṣe ìdásílè Boko Haram, nínú ìwé rẹ̀ tó kọ ní ọdún 2018, Abu Musab al-Barnawi – Slicing off the Tumor Book – June 2018[6] fi lélẹ̀ pé Kanana Taliban tí àwọn kan mọ̀ sí Nigerian Taliban ló pa Jafar Adam.[7]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named auto
  2. Webmaster (2016-06-18). "Sheikh Ja'afar Adam: Same emotions 9 years after". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-04-19. 
  3. "Boko Haram suspected after cleric killed in Nigeria" (in en). www.thesundaily.my. https://www.thesundaily.my/archive/945944-MRARCH239712. 
  4. "Boko Haram suspected after cleric killed in Nigeria - International - World" (in en). Ahram Online. http://english.ahram.org.eg/NewsContent/2/9/93249/World/International/Boko-Haram-suspected-after-cleric-killed-in-Nigeri.aspx. 
  5. Tukur, Sani (2017-04-30). "What Nigeria Police found in Senator Goje’s home concerning Sheikh Ja’afar’s murder". www.premiumtimesng.com. Retrieved 2024-09-10. 
  6. "Abu Musab al-Barnawi – Slicing off the Tumor Book – June 2018". Unmasking Boko Haram: Exploring Global Jihad in Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-05-10. Retrieved 2024-07-09. 
  7. "Case Not Quite Closed on the Assassination of Nigerian Salafi Scholar Shaikh Jaafar Adam | Council on Foreign Relations". www.cfr.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-07-09.