Jackie Robinson
Jack Roosevelt "Jackie" Robinson (January 31, 1919 – October 24, 1972) ni adulawo akoko to gba boolu ni Major League Baseball (MLB) ni igba odeoni.[1] Robinson bori iseeleyameya nigba to bere si ni gba boolu fun egbe agba baseball Brooklyn Dodgers ni 1947. Gegebi alawodudu akoko to gba baseball ni idije na lati eyin ewadun 1880, o kopa koko ninu mimu iwa ipinsoto eleya wa sopin ninu ere baseball, eyi to ti fa awon agba boolu alawodudu si pe ki won o mo gba boolu ni Negro leagues nikan fun ogota odun.[2]
Jackie Robinson | |
---|---|
Second baseman | |
Born: Cairo, Georgia | Oṣù Kínní 31, 1919|
Died: October 24, 1972 Stamford, Connecticut | (ọmọ ọdún 53)|
Batted: Right | Threw: Right |
MLB debut | |
April 15, 1947 for the Brooklyn Dodgers | |
Last MLB appearance | |
October 10, 1956 for the Brooklyn Dodgers | |
Career statistics | |
Batting average | .311 |
Hits | 1,518 |
Home runs | 137 |
Runs batted in | 734 |
Stolen bases | 197 |
Teams | |
Negro leagues International League Major League Baseball | |
Career highlights and awards | |
| |
Member of the National | |
Baseball Hall of Fame | |
Induction | 1962 |
Vote | 77.5% (first ballot) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |