Jacqueline Kennedy Onassis
Olóṣèlú
Jacqueline "Jackie" Lee Bouvier Kennedy Onassis (pronounced /ˌdʒækˈliːn ˈliː ˈbuːvieɪ ˈkɛnɪdi oʊˈnæsɪs/;[2] July 28, 1929 – May 19, 1994)[1] je iyawo John F. Kennedy nigbato je Aare Orile-ede Amerika 35k, ohun si lo wa bi Iyaafin Akoko Orile-ede Amerika nigba ise Aare oko re lati 1961 titi di igba to je fifikupa ni 1963. Leyin odun marun lati igba yi o fe Aristotle Onassis; won fe ara titi di igba ti Aristotle Onassis ku ni 1975.
Jacqueline Bouvier Kennedy | |
---|---|
Official White House portrait | |
First Lady of the United States | |
In office January 20, 1961 – November 22, 1963 | |
Asíwájú | Mamie Eisenhower |
Arọ́pò | Lady Bird Johnson |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Bellport, New York, United States | Oṣù Keje 28, 1929
Aláìsí | May 19, 1994[1] New York City, United States | (ọmọ ọdún 64)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic |
(Àwọn) olólùfẹ́ | John F. Kennedy (1953–1963, his death) Aristotle Onassis (1968–1975, his death) |
Àwọn ọmọ | Arabella Kennedy (1956–1956) Caroline Bouvier Kennedy (born 1957) John Fitzgerald Kennedy Jr. (1960–1999) Patrick Bouvier Kennedy (1963–1963) |
Alma mater | Vassar College – attended Sorbonne – attended The George Washington University (Bachelor of Arts) |
Occupation | First Lady of the United States Book editor at Viking Press (1975–1977) Book editor at Doubleday (1978–1994) |
Signature |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedFirstLadies
- ↑ Diane Sawyer (June 14, 2011). "Jacqueline Kennedy: In Her Own Words". ABC. http://www.hulu.com/watch/278034/jacqueline-kennedy-in-her-own-words. Retrieved 15 September 2011.