Jadranka Kosor (Àdàkọ:IPA-sh; ojoibi July 1, 1953) je oloselu ati oniroyin tele ara orile-ede Croatia. O di obinrin akoko to je Alakoso Agba ile Kroatia ni July 6, 2009, leyin igbati Ivo Sanader to je Alakoso Agba tele kosesile.

Jadranka Kosor
Prime Minister of Croatia
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
6 July 2009
ÀàrẹStjepan Mesić
Ivo Josipović (Elect)
AsíwájúIvo Sanader
Vice Prime Minister
In office
23 December 2003 – 6 July 2009
Serving with Damir Polančec, Đurđa Adlešič, Slobodan Uzelac
Alákóso ÀgbàIvo Sanader
Minister of Family, Veterans' Affairs and Intergeneration Solidarity
In office
23 December 2003 – 6 July 2009
Alákóso ÀgbàIvo Sanader
Arọ́pòTomislav Ivić
President of the Croatian Democratic Union
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
2009
AsíwájúIvo Sanader
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Keje 1953 (1953-07-01) (ọmọ ọdún 71)
Pakrac, PR Croatia, FPR Yugoslavia (now Croatia)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúCroatian Democratic Union
Alma materUniversity of Zagreb
ProfessionJournalist
Lawyer