Jagua Nana ni ìwé àkàgbádùn tí Cyprian Ekwensi kọ ní ọdún 1961.[1] Wọ́n kọ́kọ́ gbé ìwé yí jáde ní ọdún 1975, lábẹ́ ilé-iṣẹ́ Heinemann African Publisher.

Ìwé yí da lórí iyè-méjì tí ó ń ṣẹlẹ̀ẹ̀ nínú ayé obirin tí ó jẹ́ olówò nàbì tí ó ti ń dàgbà (Jagua Nana) tí ó jẹ́ olú-èdá ìtàn. [2] The novel is set in the city of Lagos.[3] Oríṣiríṣi àyẹ̀wò ni wọ́n ti fi ìwé yí ṣe pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ ònkọ̀wé Charles Dickens, àwọn ayẹ̀wò wọ̀nyí da lè ìgbé ayé àwọn ènìyàn ní inú àwọn ìlú tó ti lajú àti àríwísí nípa ìsòro àwọn ènìyàn tí ó ń gbé nínú àwọn ìlú wọnyí. [2][3] Critics of the work in the 1980s noted that the novel relies heavily on stereotypical depictions of women, hampering its depiction of life in Africa.[1]

Àwọn Itọ́ka sí

àtúnṣe

Ẹ kà síwájú si

àtúnṣe


Àdàkọ:1960s-novel-stub Àdàkọ:Nigeria-novel-stub