Jake Obetsebi-Lamptey
Jacob "Jake" Lantei Otanka Obetsebi-Lamptey (4 February 1946 – 20 March 2016) jẹ́ olóṣèlú àti olùpolongo oníṣòwò ọmọ orílẹ̀ ède Ghana.[1] Òun ni ó ni Lintas W.A., òun náà sì ni alákoso àgbà ilé iṣẹ́ náà láti ọdún 1974 títí di ìgbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ń bá ìjọba John Kufuor ṣiṣẹ́ ní ọdún, ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ìjọba John Kufour láti ọdún 2001 títí di ọdún 2007. Òun ni ó jẹ́ alága New Patriotic Party láti 2010 di 2014.[1]
Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeA bí Jake ní ọjọ́ kẹrin oṣù kejì ọdún born 1946 ní Accra, Ghana, ó jẹ́ ọmọ Emmanuel Obetsebi-Lamptey, ẹni tí ó jẹ́ agbejọ́rò àti olọ́sẹ̀lú, àti wife Margaretha,[2] Jake Obetsebi-Lamptey ka ìwé prámárì rẹ̀ ní Accra, kí ó tó lọ England láti tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú.
Ikú rẹ̀
àtúnṣeObetsebi-Lamptey fi ayé sílẹ̀ ní ilé ìwòsàn kan ní ní ọjọ́ ogún oṣù kẹta ọdún 2016, ó jẹ́ ọmọ ọdún àádọ́rin nígbà ikú rẹ̀.[3][4] Ó ti ń bá àìsàn leukemia fínra fún ìgbà díẹ̀ kí ó tó kú, ó sì ún gba ìwòsàn ní orílẹ̀ èdè South Africa.[5][6]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Agbeko, Peter (14 April 2016). "WELCOME HOME: Jake The Statesman". modernghana.com. Retrieved 9 September 2021.
- ↑ Biography, Jake Obetsebi-Lamptey.
- ↑ "Jake’s death: March is a sad month – Mahama", GhanaWeb, 20 March 2016.
- ↑ "Jake Obetsebi Lamptey has died". The New Statesman. 20 March 2016. Archived from the original on 31 March 2016. https://web.archive.org/web/20160331231727/http://thestatesmanonline.com/index.php/politics/1586-jake-obetsebi-lamptey-has-died.
- ↑ Sena Quashie, "Late NPP chairman died of blood cancer" Archived 2016-10-06 at the Wayback Machine., Pulse.com, 21 March 2016.
- ↑ Kobby Asmah & Emmanuel Ebo Hawkson, "Nation mourns Jake Obetsebi-Lamptey", Graphic Online, 21 March 2016.