Jalingo
Jalingo ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Taraba ní ariwa ìwọ oòrùn Nàìjíríà , Jalingo ní èdè fulfulde túmọ̀ sí "ibi gíga", ó sì ní olùgbé 418,000. Àwọn Fulani àti àwọn ẹ̀yà kẹ́kẹ̀ kẹ́ mìíràn ni ó wà ní ìlú Jalingo.[1] Fulfulde, Mumuye, Hausa àti àwọn èdè míràn ni wọ́n ń sọ ní Jalin
Jalingo | |
---|---|
Afárá kan ní agbègbè Jalingo | |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Ipinle | Taraba |
Agbegbe Ijoba Ibile | Jalingo |
Alámòjútó Alága
àtúnṣeÌjọba ìbílè kọ̀ọ̀kan ní Nàìjíríà lóní alámòjútó alága tó ń darí wọn. Àwọn ni wọ́n ń darí ètò ìpílẹ̀.
Alága tí wọ́n yàn ní Jalingo ní ètò ìdìbò 2020 tó kọjá[2] ni Hon. Abdulnaseer Bobboji ti ẹgbẹ́ òṣẹ̀lú People Democratic Party (PDP).[3] Ó ti jẹ́ alámòjútó alága títí tó fi parí àsìkò rẹ̀ ní ọjọ́ Àìkú, oṣù kéje, ọdún 2022.[4][5] gómínà ipínlẹ̀ Taraba Arch. Darius Dickson Ishaku yan aṣojú ètò-ìlera Primary Health Care Development Agency Alh. Aminu Jauro gẹ́gẹ́ bí alámòjútó alága tí Jalingo.[6][7]
Ọjà
àtúnṣeJalingo jẹ́ olú-ìlú ìpínlẹ̀ Taraba ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjà ṣùgbọ́n àwọn ọjà tó gbajúmọ̀ jù.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "The World Gazeteer". Archived from the original on 2013-02-09. Retrieved 2007-04-06. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Royal, David O. (2020-06-09). "Taraba holds LG election June 30". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-31.
- ↑ Report, Agency (2017-02-27). "PDP sweeps elections in Taraba, Gombe, Rivers". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-31.
- ↑ admin (2022-07-03). "PRESS RELEASE: Gov. Ishaku Approves the Dissolution of Local Government Councils". TARABA STATE GOVERNMENT (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-12-31. Retrieved 2022-12-31.
- ↑ admin (2022-07-01). "PRESS RELEASE: LGA Chairmen, Councillors Tenures Ends in Few Days". TARABA STATE GOVERNMENT (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-12-31. Retrieved 2022-12-31.
- ↑ NNN (2022-09-06). "Ex-Taraba primary healthcare secretary assumes office as LG chairman". NNN (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-12-31. Retrieved 2022-12-31.
- ↑ admin (2022-07-03). "PRESS RELEASE: Gov. Ishaku Approves the Dissolution of Local Government Councils". TARABA STATE GOVERNMENT (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-12-31. Retrieved 2022-12-31.
- ↑ "Fuel scarcity, high food prices, others may mar Yuletide in Taraba". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-12-23. Archived from the original on 2022-12-31. Retrieved 2022-12-31.
- ↑ says, Babalola James Olatunde (2022-08-19). "Mu’azu Jaji Sambo, an Unassuming Achiever" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-31.