James Adomian

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

James Adomian (ọjọ́ ọ̀kànlélọ́gbọ̀n oṣù kínín ọdún 1980) jẹ́ aláwàdò àti òṣèré ará Amẹ́ríkà. Ó jẹ́ ìran Armenia.[1] Wọ́n mọ Adomian fún ọ̀pọ̀lọpò. eré ìtàgé tí ó ti ṣe bíi Vincent Price, Lewis Black, Orson Welles, Jesse Ventura, Paul Giamatti, Michael Caine, Philip Seymour Hoffman àti Comedy Bang! Bang!.[2]

James Adomian (2016)

Àwọn ìtókasíÀtúnṣe