James Wilson Robertson
James Wilson Robertson | |
---|---|
Fáìlì:James Wilson Robertson.jpeg Portrait by Walter Bird, 1965 | |
2nd Governor-General of Nigeria | |
In office 15 June 1955 – 16 November 1960 | |
Asíwájú | John Stuart Macpherson |
Arọ́pò | Nnamdi Azikiwe |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Broughty Ferry, Dundee, Scotland | 27 Oṣù Kẹ̀wá 1899
Aláìsí | 23 September 1983 United Kingdom | (ọmọ ọdún 83)
Education | Merchiston Castle School |
Alma mater | Balliol College, Oxford |
Occupation | Civil servant |
Military service | |
Branch/service | British Army |
Unit |
Ẹni-ọwọ̀ James Wilson Robertson jẹ́ òṣìṣẹ́-ìjọba ọmọ orílẹ̀-èdè tí ó ṣojú ìjọba Bíríkò lórílẹ̀-èdè Nigeria láti ọdún 1955 sí 1960.
Ìgbésí-ayé rẹ̀ láti èwe àti ìkẹ́kọ̀ọ́
àtúnṣeÓ kẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ìwé Merchiston Castle School ní ìlú Edinburgh àti Balliol College, Oxford. Ó ṣiṣẹ́ sin ìjọba Bìrìtìkó lẹ́kà tó ń mójú tó àwọn ológun, British Army pẹ̀lú ẹ̀ka ọmọ-ogun Gordon Highlanders àti Black Watch. Wọ́n dá a lọ́lá oyè Ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ - òfin, Doctor of Laws láti University of Leeds lọ́dún 1961.[1]
Iṣẹ́
àtúnṣeLẹ́yìn Oxford, ó dara pọ̀ mọ́ iṣẹ́ òṣèlú Sudan, Sudan Political Service ní ọdún 1922 sí 1953, bẹ́ẹ̀ náà ó ṣiṣẹ́ ní àgbègbè ìṣèjọba Blue Nile, White Nile, Fung, àti Kordofan, bákan náà ó jẹ́ akọ̀wé ilé-ìṣẹ́ ìjọba láti ọdún 1945 sí 1953. Ní àkókò yìí ni Akọ̀wé-yànyàn àwọn orílẹ̀-èdè tí ìjọba Bìrìtìkó ń ṣàkóso, Ọ̀gbẹ́ni Oliver Lyttelton rán-an sí British Guiana lóṣù kìíní ọdún 1954 láti ṣe àkọsílẹ̀ ìjábọ̀ èsì Robertson Commission láti ṣe ìwádìí rògbòdìyàn tí ó bẹ́ sílẹ̀ nígbà náà látàrí ìdìbò tí ó gbé ẹgbẹ́-òṣèlú People's Progressive Party, tí wọ́n fẹ̀sùn kàn lásìkò náà pé wọ́n ti ń bá àwọn elétò ìṣèjọba aláṣepọ̀,Communist tí wọ́n ṣokùnfà fífagilé òfin fún ìgbà díẹ̀.[2][3][4]
Lẹ́yìn àṣeyọrí tó lóòrì tí ó ṣe, èyí ló mú wọn rán-an sí orílẹ̀-èdè Nigeria. Òun ni aṣojú ìjọba Bìrìtìkó, tí ó ṣojú Ààrẹ-bìnrin, Queen Elizabeth II ni Nigeria láti ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹfà ọdún 1955 sí ọjọ́ kẹrìndínlógún, oṣù kọkànlá ọdún 1960.[5]
Mọ̀lẹ̀bí
àtúnṣeÀbúrò rẹ̀ ni Ian Robertson, Lord Robertson, tí ọmọ rẹ̀, Sally[6] fẹ́ Nick Kuenssberg Àdàkọ:P-n.[7] Ọmọ ẹ̀gbọ́n rẹ̀, Laura Kuenssberg jẹ́ oníròyìn.[8]. Ìyàwó rẹ̀ àkọ́kọ́ ni Anne Mueller.
Ìṣọ̀wọ́kọ̀wé
àtúnṣe- 1899 – 3 June 1931: James Wilson Robertson
- 3 June 1931 – 1940: James Wilson Robertson MBE[9]
- 1940–1941: His Excellency James Wilson Robertson MBE, Governor of Gerzira Province[10]
- 1941 – 1 January 1948: James Wilson Robertson MBE
- 1 January 1948 – 1 June 1953: Sir James Wilson Robertson KBE[11]
- 1 June 1953 – 15 June 1955: Sir James Wilson Robertson KCMG, KBE[12]
- 15 June 1955 – 1956: His Excellency Sir James Wilson Robertson KCMG, KBE, Governor-General and Commander-in-Chief, Federation of Nigeria
- 1956 – 13 June 1957: His Excellency Sir James Wilson Robertson GCVO, KCMG, KBE, Governor-General and Commander-in-Chief, Federation of Nigeria
- 13 June 1957 – 1 October 1960: His Excellency Sir James Wilson Robertson GCMG, GCVO, KBE, Governor-General and Commander-in-Chief, Federation of Nigeria[13]
- 1 October – 16 November 1960: His Excellency Sir James Wilson Robertson GCMG, GCVO, KBE, Governor-General and Commander-in-Chief of the Independent Federation of Nigeria
- 16 November 1960 – 1965: Sir James Wilson Robertson GCMG, GCVO, KBE
- 1965–1983: Sir James Wilson Robertson KT, GCMG, GCVO, KBE
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ University of Leeds List of Honorary Graduates: James Wilson Robertson 1961 Archived 10 August 2009 at the Wayback Machine.
- ↑ theyworkforyou.com British Guiana Constitution (Report)
- ↑ guyana.org Robertson Report
- ↑ guyana.org The Suspension of the British Guiana Constitution
- ↑ Worldstatesman.org Nigeria
- ↑ "Sally Kuenssberg, CBE". BBC Scotland. 31 December 1999. http://news.bbc.co.uk/1/hi/special_report/1999/12/99/new_years_honours/584140.stm. Retrieved 20 May 2010.
- ↑ "Nick Kuenssberg". Debretts. Retrieved 20 May 2010.
- ↑ Kristy Dorsey (4 March 2013). "Business interview: Nick Kuenssberg". The Scotsman. http://www.scotsman.com/business/management/business-interview-nick-kuenssberg-1-2819213. Retrieved 23 January 2016.
- ↑ The London Gazette, 3 June 1931
- ↑ [pg 1886, Who's Who, 1982]
- ↑ The London Gazette, 1 January 1948
- ↑ The London Gazette, 1 June 1953
- ↑ The London Gazette, 13 June 1957