Jane Addams
Jane Laura Addams A bí Addams ní 1860. Ó kú ní 1935. Ọmọ ilẹ̀ Àméríkà ni. Onímọ̀ nípa ẹ̀kọ́ tí wọ́n ń pè ní Sociology ni. Òun ni ó dá Hull House, Chicago sílẹ̀ ní 1889.
Jane Addams | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Cedarville, Illinois | Oṣù Kẹ̀sán 6, 1860
Aláìsí | May 21, 1935 Chicago, Illinois | (ọmọ ọdún 74)
Iṣẹ́ | American social reformer and Nobel Peace Prize recipient |
Parent(s) | John H. Addams and Sarah Weber |
Itokasi
àtúnṣe
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |