Janet Egyir jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ keje, óṣu May ni ọdun 1992. Agbabọọlu naa ṣere fun Afturelding/fram gẹgẹbi defender[1].

Janet Egyir
Personal information
Ọjọ́ ìbí7 Oṣù Kàrún 1992 (1992-05-07) (ọmọ ọdún 32)
Ibi ọjọ́ibíSekondi-Takoradi
Ìga1.62m
Playing positionDefender
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2010 – 2015Hasaacas Ladies F.C.86(16)
2015 – 2017Víkingur Ólafsvík34(8)
2018 –Afturelding/Fram18(4)
National team
Ghana women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 11 October 2014 (before the 2014 African Women's Championship)

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Janet kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ti ọdun 2014[2].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://fbref.com/en/players/5cab9401/Janet-Egyir
  2. https://ng.soccerway.com/players/janet-egyir/135330/