Janet Yang
Janet Yang (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1956) jẹ́ olùṣe fíìmù àti ààrẹ Academy of Motion Picture Arts and Sciences lọ́wọ́ lọ́wọ́, Janet jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Yang àwọn eré Janet tí ó ti fi gba àmì ẹyẹ ni The Joy Luck Club, The People vs. Larry Flynt, Dark Matter, Indictment: The McMartin Trial, Zero Effect, Shanghai Calling, High Crimes, àti eré Over the Moon, èyí tí ó mú kí wọ́n yàn mọ́ ara àwọn tí ó tó sí àmì ẹyẹ Academy.
Janet Yang | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Keje 1956 New York City, New York, U.S. |
Iṣẹ́ | Producer/Entertainment and Media Consultant |
Ìgbà iṣẹ́ | 1985– títí di ìsinsìnyí |
Àwọn ọmọ | 1 |
Ìpìlẹ̀ àti Èkó rẹ̀
àtúnṣeA bí Janet Yang ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje ọdún 1956, ní ìlú Queens ti New York. Yang lọ ilé-ìwé Phillips Exeter Academy,[1] kí ó tó lọ sí Brown University, níbi tí ó ti gbájúmọ́ ìmò Chinese, lẹ́yìn náà tí ó sì gba àmì ẹyẹ MBA ní Yunifásítì Kòlúmbíà.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Janet Yang '74 recalls Exeter's 'inclusive' environment". Phillips Exeter Academy (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-08-04. Retrieved 2022-08-10.
- ↑ Hirahara, Naomi. Distinguished Asian American Business Leaders. Greenwood Publishing Group. pp. 219–221.