Jasën Blu jẹ́ akọrin Nàìjíríà, ó tún jẹ́ òǹkọrin, agbé rẹ́kọ́dù jáde tí ó sì tún máa ń ṣe àtòjọ orin.[1] Àkọ́kọ́ gbé jáde iṣẹ́ rẹ̀,tó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Road 2 Soulwave EP jáde ní oṣù kẹwàá ọdún 2020 lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èyí tí kò bá òfin mu tó ti gbé jáde, àti ti èyí tó jẹ́ gbogbogbò, èyí tí "Already" (2017), "Brown Shuga" (2019), "Chill", àti "BluFunk" (2023) náà wà lára rẹ̀.

Jasën Blu
Ìbẹ̀rẹ̀Akure, Nigeria
Irú orin
Occupation(s)
Instruments
Years active2007–present
LabelsNubiana
Websitehttps://jasenblu.com

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Blu ní ìlú Akure, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, wọ́n sì tún tọ níbẹ̀ náà. Àkọ́kọ́ eré tó kọ́kọ́ ṣe ní ìgbé-ayé rẹ̀ jẹ́ ti èyí tó ṣe nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méjìlá,níbi tí ó ti fi ara, ojú nìkan kọ orin Angel tí Shaggy kọ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ tókù níbi ìpéjọ wọn ní ilé-ẹ̀kọ́ ti Girama ní ilé-ẹ̀kọ́ oní gbígbé.

Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga àpapọ̀ fún ìmọ̀-ẹ̀rọ ní ìlú Àkúrẹ́,lati ọdún 2004 sí 2009, ó kọ́ nípa bí a ṣe ń ṣe ètó ìlú àti agbègbè tí ó sì tún mú iṣẹ́ orin mọ́ akadá rẹ̀. Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkáhùnsílẹ́ àti ṣíṣe elégbè orin fún àwọn òṣèré akẹ́kọ̀ọ́ tókù, ó kó lọ sí ìlú Èkó ní ọdún 2008,níbi tí ó ti tẹ̀ síwájú nínú iṣẹ́ orin rẹ̀.[2]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Àlùyọ àkọ́kọ́ fún Blu wá nígbà tí wọ́n yan orin rẹ̀ "L.A.S.G.I.D.I. (Gidi Anthem)" gẹ́gẹ́ bi èyí tó gorókè jùlọ, àti pé òun ló tún jẹ́ kókó orin tó jẹ mọ́ eré òṣèré ń nì Obi Emelonye eré ládojúdé ọdún 2012, "Last Flight to Abuja",níbi tí ó ti ó ti di gbajúgbajà látàrí àṣeyọrí eré náà.[3] Lẹ́yìn náà ló gbé àwo kékeré kan jáde, àwọn bí i

Lọ́jọ́ àyàjọ́ olólùfẹ́ ní ọdún bà tí ó gbé àwo lórí à"o àkọ́kọ́ rẹ̀ tó gbé jáde.[4][5] Lẹ́yìn tí wọ́n ti gbe lọ sórí ìkànnì tọ́nrán fọ́nkálé láti kéde ni ìgbéjáde àkọ́l

After a briorin rẹ̀ tó ti wà nílẹ̀ tẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bi August 2022 with the non-album buzz single, "Otojometa"[6] In March 2023, he released SoulwaveÀdàkọ:'s second official single, "Chill" via his independent record label, Nubiana.[7] The season-themed third single, "Summertime" was released in July, which Blu hinted was inspired by hip-hop group Lost Boyz's 1997 song of the same name.[8] The fourth single, a retro-pop and funk inspired record "BluFunk" was released in September 2023.[9] In December, a remix of "BluFunk" dubbed the 'RockOut Remix' was released, featuring Nigerian Hip-Hop artist Hotyce, marking Blu's fourth and final release of 2023.[10]

Late May 2024, Blu released "Faraway (My Heart Goes...)", a neo soul and R&B record that interpolates the chorus of Nigerian pop singer Tony Tetuila's hit, "My Heart Go Jigi Jigi", reinforcing Blu's hitherto reputation for paying homage to his favorite legacy stars through music.[11]

Other ventures

àtúnṣe

SoundQraft LLC

àtúnṣe

Blu founded and operates a music production outfit, SoundQraft LLC, via which he writes, produces and engineers all his own musical recordings as well as offering the same services to other musicians. He has also recorded original soundtracks and composed original music and sound designs to many Nollywood films, the first couple of which was Emelonye's Last Flight to Abuja (original soundtrack) and his Africa Magic original television series "The Calabash" (score composition and sound design) in 2014.[1][9] He has since composed original scores and contributed recordings to a large number of Nollywood and other African feature films, shorts, television series and commercials, and has on occasions cited his works as a composer as one of the underlying factors for his delayed music releases.[1][10]

Discography

àtúnṣe

EPs

  • Road 2 Soulwave (2020)

References

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 "Jasën Blu | Composer, Music Department". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-16. 
  2. "Jasën Blu". Genius (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-07-19. 
  3. "Jasen Blu Drops a New Single "Born to Be Great"". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-07-19. 
  4. Editorial (2017-02-27). "Jasen Blu set to take music world by storm". The Difference News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-07-19. Retrieved 2019-07-19. 
  5. "Jasën Blu - 'Already'". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-04-17. Retrieved 2019-07-19. 
  6. Sledge (2022-08-29). "Audio + Video: Jasën Blu – "Otojometa"". Naija Music Hub (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2023-11-16. Retrieved 2023-11-16. 
  7. Sledge (2023-03-29). "Audio: Jasën Blu – "Chill"". Naija Music Hub (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2023-11-16. Retrieved 2023-11-16. 
  8. Sledge (2023-07-07). "Audio: Jasën Blu – "Summertime"". Naija Music Hub (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2023-11-16. Retrieved 2023-11-16. 
  9. 9.0 9.1 "Jasën Blu goes the route of legends on new single, Blufunk". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-10-07. Retrieved 2023-11-05. 
  10. 10.0 10.1 "Jasën Blu Blazes to the 2023 Finishing Line with "Blufunk" Remix - Thisdaylive". www.thisdaylive.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-12-22. 
  11. Adebayo, Segun (2024-06-16). "Jasën Blu pays homage to Tetuila in new single". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-06-16.