Jasmin Savoy Brown jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ-èdè Amẹ́ríkà. Ó ṣeré nínú fíìmù HBO tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ The Leftovers (2015–2017), eré ABC tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ For the People (2018–2019), àti eré Showtime tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ Yellowjackets (2021–present).[3] Ó tún ṣeré nínú àwọn fíìmù bi Sound of Violence (2021), Scream (2022) àti Scream VI (2023).

Jasmin Savoy Brown
Ọjọ́ìbí21 Oṣù Kẹta 1994 (1994-03-21) (ọmọ ọdún 30)[1][2]
Alameda, California, U.S.
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2013–present

Ìpìlẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Brown sí ìlú Alameda, California, wọ́n sì to dàgbà ní ìlú Springfield, Oregon.[4] Nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún merin, Brown kópa nínú orin kan ní ilé ìjọsìn tí ó ń lọ, èyí sì mú kí ó ní ìfẹ́ sí eré ṣíṣe. Bí ó ti ń dàgbà, ó kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ orin àti eré.[5] Lẹ́yìn ìgbà tí ó parí ìwé mẹ́fà, ó kó lọ sí Portland, Oregon láti lépa àlá rẹ̀ nínú eré ṣíṣe.[6]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Àdàkọ:Cite tweet
  2. Stacy Lambe (March 6, 2023). "'Yellowjackets' Star Jasmin Savoy Brown Teases a 'Very Satisfying' Start to Season 2 (Exclusive)". Entertainment Tonight. Archived from the original on April 28, 2023. Retrieved April 28, 2023.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Philip, Tom (April 26, 2017). "You Will Know Jasmin Savoy Brown". Archived from the original on April 30, 2017. 
  4. "Jasmin Savoy Brown". Archived from the original on June 8, 2016. Retrieved May 27, 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Maiolo, Derek. "Jasmin's world". Archived from the original on August 17, 2018. Retrieved January 16, 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. Barna, Ben. "For Jasmin Savoy Brown, The Leftovers Was A Dream Job". Archived from the original on January 3, 2018. Retrieved January 2, 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)