Jay Boogie
Jay Boogie (tí a bí ní Ọjọ́ Kẹrindínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹfà, Ọdún 1998)[1] jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó nífẹ̀ẹ́ nínú oge àwọn tí ń yí ìdánimọ̀ wọn láti èyí tí wọ́n wà nígbà tí wọ́n bí wọn, ẹni tó ní ipa àti àgbajúmọ̀ lórí àwọn ìkànnì àjọlò lórí ẹ̀rọ ayélujára tí ó dá JaySecrets sílẹ̀. Ó di olókìkí lórí Instagram ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún ogún rẹ̀, pẹ̀lú ìyípadà ìbálòpọ̀ rẹ̀ tí ó ń gba àfiyèsí láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Nàìjíríà lórí àwọn ìkànnì àjọlò àwùjọ. Boogie ti wà ní àkójọ láàárín àwọn tó máa ń wọṣọ ẹ̀yà ọ̀tọ̀ mẹ́wàá tí ó ga jùlọ ní Nàìjíríà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Bobrisky àti James Brown.
Jay Boogie | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kẹfà 1998 Port-Harcourt, Nigeria |
Iṣẹ́ | Social media personality |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Ngwan, Nenpan (2022-12-09). "Who Is Jay Boogie the Cross-dresser and Has He Had Surgery?". Buzz Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-11.