Jean-Michel Basquiat
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Jean-Michel Basquiat (December 22, 1960 – August 12, 1988) je onisona ara Amerika.[1] O bere bi onisona grafiti ni New York City ni opin ewadun 1970, o si se ni ewadun 1980 aworan kikun Alafarahan-tuntun. Basquiat ku nitori ilokulo heroini ni August 12, 1988, nigba to je omo odun 27.[2]
Jean-Michel Basquiat | |
---|---|
Basquiat (1984) | |
Bíbí | Oṣù Kejìlá 22, 1960 |
Kú | August 12, 1988 Manhattan, New York City, U.S. | (ọmọ ọdún 27)
Ilẹ̀abínibí | American |
Pápá | Painting |
Movement | Postmodern |
Influenced by | Jean Dubuffet, Pablo Picasso, Robert Rauschenberg, Cy Twombly, Andy Warhol |
"Basquiat" túndarí síbí yìí. Fún filmu Julian Schnabel, ẹ wo Basquiat (filmu).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Graham Thompson, American Culture in the 1980s, Edinburgh University Press, 2007, p67. ISBN 0-7486-1910-0
- ↑ Encyclopedia of the African diaspora: origins, experiences, and ..., Volume 1 By Carole Boyce Davies. ABC-CLIO. p. 150.