Jeremiah Ogonnaya Uzosike

Jeremiah Ogonnaya Uzosike ti gbogbo ènìyàn mọ si Jerry Uzosike jẹ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. O je omo ile ìgbìmọ̀ asofin ipinlẹ Abia tele to n soju àgbègbè Umuahia South. [1] [2] [3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe