Jereton Mariere
Olóṣèlú
Jereton Mariere jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti olórí Àgbègbè Àárín-ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ kí ó tó di Ìpínlẹ̀ Bendel lọ́dún 1976.
Samuel Jereton Mariere | |
---|---|
Gómìnà apá àárín-gbùngbùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà ìṣèjọba ẹlẹ́kùnjẹkùn | |
In office February 1964 – ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kìíní ọdún 1966 | |
Arọ́pò | David Ejoor |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ọdún 1907 Evwreni, Nàìjíríà Alámùúsìn |
Aláìsí | Ọjọ́ kẹsàn-án oṣù karùn-ún ọdún 1971 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |