Jerry Eze
Jerry Uchechukwu Eze tí a bí ní ọjó̩ kejìlélógún oṣù kẹjọ ọdun 1982 jẹ́ olùṣọ-àgùntànìjọ kan ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Eze jẹ́ olùdásílẹ̀ Streams of Joy International àti olùdarí New Season Prophetic Prayer and Declaration (NSPPD), at̀i ìpàdé orí afẹ́fẹ́.[1][2][3][4]
Àwon ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Nimi Princewill (21 August 2022). "The YouTube prayer channel started during Covid that's become a global movement". CNN. Retrieved 2022-09-11.
- ↑ Bp-Relate (2016-09-23). "Biography Of Pastor Jerry Uchechukwu Eze". Believers Portal (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-09-03.
- ↑ NgFinders (2020-03-05). "Biography Of Pastor Jerry Uchechukwu Eze - Ngfinders.com". NGfinders (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-09-02.
- ↑ DIFF. "Most Super Chatted Channels in Worldwide". PLAYBOARD (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-09-11.