Jet Li

eléré ìdárayá

Àdàkọ:Infobox Chinese-language singer and actor Àdàkọ:Contains Chinese text

Orúkọ ará Ṣáínà kan nìyí; orúkọ ìdílé ni Li.

Li Lianjie ([lɨ̀ ljɛ̌nt͡ɕjɛ̌]; ojoibi 26 April 1963), to gbajumo pelu oruko ori itage re ni ede Geesi bi Jet Li, je osere, atokun filmu, onimo ere-ija, ati ayori wushu ara Ṣáínà to je bibi ni Beijing. O ti di omo orile-ede Singapore.[1]ItokasiÀtúnṣe

  1. "Xinhuanet.com". News.xinhuanet.com. Retrieved October 2, 2010.