Jhumpa Lahiri

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Nilanjana Sudeshna "Jhumpa" Lahiri[1] (tí wọ́n bí ní July 11, 1967) jẹ́ òǹkọ̀wé ti Indian àti American, tí ó gbajúmọ̀ fún àwọn ìtàn kékeré rẹ̀, ìwé ìtàn-àròsọ àti àròkọ rẹ̀ ní èdè Gẹ̀ẹ́sì àti ní èdè Italy.

Jhumpa Lahiri
Jhumpa Lahiri in 2015
Ọjọ́ ìbíNilanjana Sudeshna Lahiri
Oṣù Keje 11, 1967 (1967-07-11) (ọmọ ọdún 56)
London, England
Iṣẹ́Author
Ọmọ orílẹ̀-èdèAmerican
Alma mater
Ìgbà21st century
GenreNovel, short story, postcolonial
Notable works
Notable awards
Website
randomhouse.com/kvpa/jhumpalahiri/

À̀tòjọ ìtàn kékeré rẹ̀ ni Interpreter of Maladies (1999) tó gba ẹ̀bùn Pulitzer Prize for Fiction àti ẹ̀bùn PEN/Hemingway Award, ìwé ìtàn-àròsọ rẹ̀, The Namesake (2003), ni ó fàyọ nínú fíìmù àgbéléwò The Namesake.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ àtúnṣe

Wọ́n bí Lahiri sí ìlú London, ó sì jẹ́ ọmọbìnrin ti àwọn ará India tó sí lọ sí West Bengal. Ìdílé rẹ̀ kó lọ sí United States nígbà tó wà ní ọmọ-ọdún mẹ́ra; Lahiri máa ń rí ara rẹ̀ bí i ará America, ó sì máa ń sọ pé, "Wọn ò bí mi síbi àmọ́ ó ṣe é ṣe kó jẹ́ bẹ́ẹ̀."[2] Lahiri dàgbà sí Kingston, ní Rhode Island, níbi tí bàbá rẹ̀, ìyẹn Amar Lahiri ti ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i librarian ní University of Rhode Island;[2] ìwé "The Third and Final Continent", ìtàn tó parí Interpreter of Maladies, jẹ́ èyí tó kọ nípa bàbá rẹ̀.[3] Ìyá Lahiri fẹ́ kí àwọn ọmọ òun dàgbà sí mímọ àṣà Bengali, àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ sì máa ń wá wò wọ́n dáadáa ní Calcutta.[4]

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ àtúnṣe

  • 1993 – TransAtlantic Award from the Henfield Foundation
  • 1999 – O. Henry Award for short story "Interpreter of Maladies"
  • 1999 – PEN/Hemingway Award (Best Fiction Debut of the Year) for "Interpreter of Maladies"
  • 1999 – "Interpreter of Maladies" selected as one of Best American Short Stories
  • 2000 – Addison Metcalf Award from the American Academy of Arts and Letters
  • 2000 – "The Third and Final Continent" selected as one of Best American Short Stories
  • 2000 – The New Yorker Best Debut of the Year for "Interpreter of Maladies"
  • 2000 – Pulitzer Prize for Fiction for her debut "Interpreter of Maladies"
  • 2000 – James Beard Foundation's M.F.K. Fisher Distinguished Writing Award for "Indian Takeout" in Food & Wine Magazine
  • 2002 – Guggenheim Fellowship
  • 2002 – "Nobody's Business" selected as one of Best American Short Stories
  • 2008 – Frank O'Connor International Short Story Award for "Unaccustomed Earth"
  • 2009 – Asian American Literary Award for "Unaccustomed Earth"
  • 2009 – Premio Gregor von Rezzori for foreign fiction translated into Italian for "Unaccustomed Earth" ("Una nuova terra"), translated by Federica Oddera (Guanda)
  • 2014 – DSC Prize for South Asian Literature for The Lowland[5]
  • 2014 – National Humanities Medal[6]
  • 2017 – Pen/Malamud Award
  • 2023 – Honorary Doctorate from The American University of Rome in recognition of her extraordinary contribution to literature in English and Italian.[7]

Àtòjọ iṣẹ́ rẹ̀ àtúnṣe

Ìwé ìtàn-àròsọ àtúnṣe

Àwọn ìtàn kékeré àtúnṣe

  • Interpreter of Maladies (1999)
    • "A Temporary Matter" (previously published in The New Yorker)
    • "When Mr. Pirzada Came to Dine" (previously published in The Louisville Review)
    • "Interpreter of Maladies" (previously published in the Agni Review)
    • "A Real Durwan" (previously published in the Harvard Review)
    • "Sexy" (previously published in The New Yorker)
    • "Mrs. Sen's" (previously published in Salamander)
    • "This Blessed House" (previously published in Epoch)
    • "The Treatment of Bibi Haldar" (previously published in Story Quarterly)
    • "The Third and Final Continent"
  • Unaccustomed Earth (2008)
    • "Unaccustomed Earth"
    • "Hell-Heaven" (previously published in The New Yorker)
    • "A Choice of Accommodations"
    • "Only Goodness"
    • "Nobody's Business" (previously published in The New Yorker)
    • "Once In A Lifetime" (previously published in The New Yorker)
    • "Year's End" (previously published in The New Yorker)
    • "Going Ashore"
    • "Hema and Kaushik"
  • Racconti romani (in Italian). Rome: Guanda. 2022.
    • "Il confine" (The Boundary)
    • "La riunione" (The Reunion)
    • "Le feste di P." (P.s Parties)
    • "Casa luminosa" (Luminous House)
    • "La scalinata" (The Stairway)
    • "Il ritiro" (Withdrawal)
    • "La processione" (The Procession)
    • I bigliettini (The Cards)
    • Dante Alighieri

Àwọn ìtàn àtúnṣe

Ewì àtúnṣe

  • Il quaderno di Nerina (Italian) (2020)

Adálérí-ìtàn-gidi àtúnṣe

Ìwé àtúnṣe

  • In altre parole (Italian) (2015) (English translation published as In Other Words, 2016)
  • Il vestito dei libri (Italian) (English translation published as The Clothing of Books, 2016)
  • Translating Myself and Others (2022)

Àròkọ, ìjábọ̀ ìròyìn àti àwọn àfikún mìíràn àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Minzesheimer, Bob. "For Pulitzer winner Lahiri, a novel approach" Archived July 4, 2012, at the Wayback Machine., USA Today, August 19, 2003. Retrieved on 2008-04-13.
  2. 2.0 2.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named usa2
  3. Flynn, Gillian. "Passage To India: First-time author Jhumpa Lahiri nabs a Pulitzer," Archived December 31, 2008, at the Wayback Machine. Entertainment Weekly, April 28, 2000. Retrieved on 2008-04-13.
  4. Aguiar, Arun. "One on One With Jhumpa Lahiri" Archived October 7, 2008, at the Wayback Machine., Pifmagazine.com, July 28, 1999. Retrieved on 2008-04-13.
  5. Claire Armitstead (January 22, 2015). "Jhumpa Lahiri wins $50,000 DSC prize for south Asian literature". The Guardian. Archived from the original on January 29, 2015. Retrieved January 22, 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "President Obama to Award 2014 National Humanities Medal". National Endowment for the Humanities. September 3, 2015. Archived from the original on January 6, 2017. Retrieved September 4, 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "American University of Rome, lauree honoris causa per Jhumpa Lahiri e Carlo Petrini". La Stampa. May 25, 2023. Archived from the original on May 29, 2023. Retrieved May 29, 2023.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "Life lessons to learn from The Namesake by Jhumpa Lahiri| Kaitholil.com". kaitholil.com. Archived from the original on October 9, 2022. Retrieved 2022-08-02.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. "Whereabouts by Jhumpa Lahiri". Penguin Random House. Archived from the original on May 19, 2022. Retrieved December 26, 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  10. Title in the online table of contents is "In translation".