Jide Kosoko

Òṣéré orí ìtàgé

Ọmọba Jídé Kòsọ́kọ́ jẹ́ ògbónta òṣèré àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.[1][2][3][4][5]

Ìgbà èwé àti ìrínàjò iṣẹ́ rẹ̀.

àtúnṣe

Wọ́n bíi ní Ọjọ́ kejìlá Oṣù kínín Ọdún 1954 ní ìlú èkó sí ìdílé ọlọ́ba Kosoko ti erékùṣù èkó. Ó kàwé nípa okùn-òwò ní Yaba College of Technology.[6] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe bí ọmọdé òṣèré ní ọdún 1964 ní eré Makanjuola tí wọ́n máa ṣàfihàn rẹ̀ ní amóhùnmáwòran. Ó ti kópa nínú oríṣiríṣi eré ti Nollywood ní èdè Yorùbá àti ní èdè gẹ̀ẹ́sì.[7]


Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Ó fẹ́ ìyàwó méjì; Karimat àti Henrietta[6] pẹ̀lú àwọn ọmọ àti ọmọọmọ.[2]

Àwọn eré tí ó ti ṣe

àtúnṣe
  • The Department (2015)[8]
  • Gidi Up (2014) (TV Series)
  • Doctor Bello (2013)
  • The Meeting (2012)
  • Last Flight to Abuja (2012)
  • I'll Take My Chances (2011)
  • The Figurine (2009)
  • Jenifa

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe

Àwọn àjápọ̀ látìta

àtúnṣe