Jo-anne Reyneke
Jo-Anne Reyneke (bíi ni ọjọ́ kejì oṣù kẹfà ọdún 1988) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá Pearl tí ó kó nínú eré Muvhando àti Prudence Oliphant nínú Rythm City.[1]
Jo-anne Reyneke | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Jo-anne Reyneke 2 Oṣù Kẹfà 1988 Vereeniging, Gauteng, South Africa |
Ẹ̀kọ́ | Russell High School (Pietermaritzburg) |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2008 - present |
Alábàálòpọ̀ | Thami Mngqolo (2008-18) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bíi sì ìlú Vereeniging ni ilẹ̀ Guateng. [2]Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Russell High School, níbẹ̀ sì ni ó ti nifẹ sí eré ṣíṣe. Ó tesiwaju sì ilẹ̀ ẹ̀kọ́ Movietech Film and Television School ní Durban níbi tí ó tí kẹ́kọ̀ọ́ orin kíkọ àti eré ṣíṣe.[3]
Iṣẹ́
àtúnṣeÓ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ni ilẹ̀ iṣẹ́ The Playhouse Company, níbi tí ó tí kópa nínú eré The Game. Duma Ndlovu tí ó jé olùdarí ère Muvhango, fún Reyneke ni anfaani lati kópa nínú eré náà gẹ́gẹ́ bíi Pearl, èyí sì lo je ki Reyneke tí gbajúmọ̀.[4] Ní ọdún 2013, ó fi eré Muvhango sílẹ̀, ó sì kópa nínú eré Intersexions àti Rhythm City ni ọdún náà. Ní ọdún 2019, ó kópa nínú eré ẹ̀fẹ̀ tí àkọ́rí rẹ̀ jẹ́ Black Tax.[5]
Ìgbéyàwó rẹ
àtúnṣeNí ọdún 2008, Jo-Anne Reyneke ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Thami Mngqolo. Wọn bíi ọmọ méjì tí orúkọ wọn jẹ́ Uvolwethu(bíi ní ọdún 2013) àti Lungelo(bíi ni ọdún 2015). Ní ọdún 2018, òhun àti ọkọ rẹ̀ pínyà.[6][7]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Jo-anne Reyneke". 7 June 2016. https://www.tvsa.co.za/actors/viewactor.aspx?actorid=16606. Retrieved 24 April 2020.
- ↑ "10 Things You Didn’t Know About Joanne Reyneke". 7 June 2016. Archived from the original on 17 October 2020. https://web.archive.org/web/20201017123916/https://www.youthvillage.co.za/2016/07/10-things-you-didnt-know-about-joanne-reyneke/. Retrieved 24 April 2020.
- ↑ "10 Things You Didn’t Know About Joanne Reyneke". 28 March 2018. https://www.timeslive.co.za/tshisa-live/tshisa-live/2018-03-28-jo-anne-reyneke-on-being-targeted-for-her-whiteness-theyd-ask-me-to-speak-english/. Retrieved 24 April 2020.
- ↑ "WATCH: Jo-Anne Reyneke Secures Lead Role On New Comedy Series". 4 December 2019. https://zalebs.com/tv/watch-jo-anne-reyneke-secures-lead-role-on-new-comedy-series. Retrieved 24 April 2020.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Mgujulwa, Nolusindiso. "Jo-Anne Reyneke bags role in new BET comedy show". Drum (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-08-23.
- ↑ "Jo-Anne Reyneke sets the record straight on marriage rumors". 8 July 2019. https://www.w24.co.za/Lifestyle/jo-anne-reyneke-sets-the-record-straight-on-marriage-rumors-20190708. Retrieved 24 April 2020.
- ↑ "Jo-Anne Reyneke on dating as a single mother: "Once kids are involved, everything changes"". 31 January 2020. https://www.parent24.com/Lifestyle/once-kids-are-involved-everything-changes-joanne-reyneke-on-dating-as-a-single-mother-20200128. Retrieved 24 April 2020.