Jo Van Fleet
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Jo Van Fleet | |
---|---|
Van Fleet, c. 1955 | |
Ọjọ́ìbí | Catherine Josephine Van Fleet[1] Oṣù Kejìlá 29, 1915 Oakland, California, U.S. |
Aláìsí | June 10, 1996 Jamaica, New York, U.S. | (ọmọ ọdún 80)
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1944–1986 |
Olólùfẹ́ | William G. Bales (m. 1946; his death 1990) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Catherine Josephine Van Fleet (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkọ̀ndílọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá, ọdún 1915[1] tí ó sì fi ayé lè ní Ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹfà, ọdún 1996) jẹ́ Òṣèrè orí-ìtàgé, fíìmù àti Tẹlẹfísọ̀n Amẹ́ríkà. Ní gbogbo ìgbà pípẹ́ tó fi ṣe eré, níbi ọdún ogójì, ó sáábà máa ń kópa ẹni tó ju ọjọ́ orí ẹ̀ lọ. Van Fleet gba Tony Award ní ọdún 1954 fún ipa rẹ̀ ní Broadway tí The Trip to bountiful sẹ àti wí pé n tún gba àwọ́ọ̀dù Akadẹ́mì fún Òṣèrè tó ṣe igi lọ́gbà èyí fún olórí Òṣèrè ní
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "The Birth of Cathrin Vanfleet [sic]sic]", online database of California birth records, 1905-1995; californiabirthindex.org. Retrieved September 2, 2015.
- ↑ Vallance, Tom. "Obituary: Jo Van Fleet", The Independent (London), June 20, 1996. Retrieved November 21, 2013.