Joana Foster
Joana Foster (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùndínlógún oṣù kejì ọdún 1946, tí ó sì kú ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kọkànlá ọdún 2016) jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn ti orílẹ̀-èdè Ghana tó sì tún tan mọ́ orílẹ̀-èdè Britain. Iṣẹ́ agbẹjọ́rò ni arábìnrin yìí yàn láàyò.[2]
Joana Foster | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kejì 1946 |
Aláìsí | 5 November 2016 | (ọmọ ọdún 70)
Orílẹ̀-èdè | Ghanaian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | |
Iṣẹ́ | Lawyer, Women's rights activist |
Movement | Feminism, Nuclear disarmament[1] |
Board member of | AWDF, WILDAF |
Olólùfẹ́ | Michael Foster |
Ẹbí | Richard Wilkinson and Helen Wilkinson |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeÌlú Ghana ní wọ́n bí Joana sí, ilé-ìwé Achimota School ni ó lọ.[3]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣeIṣẹ́ agbẹjọ́rò ni Joana yàn láàyò.
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeJoana ṣe ìdásílẹ̀ African Women's Development Fund pẹ̀lú Bisi Adeleye-Fayemi àti Hilda M. Tadria ní ọdún 2000.[4]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "WHRD Tribute". AWID Women's Right. AWID Women's Right. Retrieved 6 May 2017.
- ↑ "LOUD WHISPERS: Joana Silochina Foster (1946-2016)". Above Whispers. Above Whispers. Retrieved 4 March 2017.
- ↑ Sekyiamah, Nana Darkoa. "Joana Foster: 'She made African women realise they can do anything'". The Guardian. The Guardian. Retrieved 6 May 2017.
- ↑ "Joana Foster: 'She made African women realise they can do anything'". The Guardian. Guardian. Retrieved 4 March 2017.