Joana Olu Maduka (bíi ni ọjọ́ kẹfa oṣù karùn-ún ọdún 1941) jẹ́ onímọ̀ iṣẹ́-ẹ̀rọ ará ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má dára pọ mọ ẹgbẹ́ Council for the Regulation of Engineering in Nigeria (COREN), Institution of Electrical Engineers, Nigerian Society of Engineers àti Nigerian Academy of Engineering. Wọ́n fí jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Nigerian Institute of Science and Technology ni ọdún 1987 àti Yaba college of Technology ni ọdún 1988.[1] Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má je adárí ẹgbẹ́ COREN.[2]

Joana Maduka
Ọjọ́ìbí6 Oṣù Kàrún 1941 (1941-05-06) (ọmọ ọdún 83)
Iṣẹ́Engineer

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọn bí Maduka ni ọjọ́ kẹfa oṣù karùn-ún ọdún 1941 ni ìlú Iléṣa ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun. Òun ni àkọ́bí ọmọ fún ogbeni Daniel Dada àti arábìnrin Olufunmilayo Layinka. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Otapete Methodist School fun ẹ̀kọ́ primary school. Ó padà lọ sí Methodist Girls school àti Queen's School ni 1955. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Ìfẹ́ ni ọdún 1965 níbi tí ó ti gbà B.SC nínú Applied Physics. Ó gbà M.Sc nínú engineering láti ilé ẹ̀kọ́ Trinity College ni orile-ede Dublin ni ọdún 1969.

Iṣẹ́

àtúnṣe

Maduka ṣiṣẹ́ gẹgẹ bii enjinia oluranlowo fún ilé iṣẹ́ Western Nigerian Television (WNTV) ni Ìbàdàn ni odun 1965. Ó dì í olùkọ́ fún ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Ìfẹ́ ni ọdún 1966 títí di 1970.

Ní ọdún 1993, Maduka dá ìgbìmọ̀ ọ̀rẹ́ Àyíká kalẹ èyí tí ó wà láti dẹ́kun ìdọ̀tí àti láti rán àwọn obìnrin lọ́wọ́. Òun na lọ dá ìgbìmò ẹgbẹ́ Association of Professional Women Engineers of Nigeria (APWEN).[3] Maduka founded the Association of Professional Women Engineers of Nigeria (APWEN).[4][5][6]

Ó di alakoso kẹsàn-án àti obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má dárí ẹgbẹ́ Nigeria Academy of Engineering ni ọjọ́ kẹta lélógún, oṣù kẹfà ọdún 2016.[7][8][9][10][11][12][13][14][15][16][17][18][19]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Amana, Destiny. "The Nigeria Academy of Engineering Fellows Profile :: promoting excellence in technology and engineering training and practice to ensure the technological growth and economic development of Nigeria". www.nae.org.ng (in English). Archived from the original on 2021-02-27. Retrieved 2020-05-11. 
  2. Moses, Akawe. "Women Breaking the Bounds | The Voice News Paper". [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "Ẹda pamosi". guardian.ng. Archived from the original on 2020-08-13. Retrieved 2020-05-11. 
  4. "Ẹda pamosi". guardian.ng. Archived from the original on 2020-09-18. Retrieved 2020-05-11. 
  5. "Ẹda pamosi". guardian.ng. Archived from the original on 2021-11-27. Retrieved 2020-05-11. 
  6. "Ẹda pamosi". guardian.ng. Archived from the original on 2021-01-25. Retrieved 2020-05-11. 
  7. Engineers, My (21 June 2016). "WHO IS THE 9th PRESIDENT OF THE NIGERIAN ACADEMY OF ENGINEERING - ENGR. MRS. J. O. MADUKA, FNSE, MFR ?". My Engineers. 
  8. "Ẹda pamosi". guardian.ng. Archived from the original on 2021-11-27. Retrieved 2020-05-11. 
  9. Engineers, My (30 April 2019). "APWEN GEARS UP FOR SECOND EDITION OF OLUTUNMBI JOANNA MADUKA ANNUAL LECTURE". My Engineers. 
  10. "Ẹda pamosi". guardian.ng. Archived from the original on 2021-10-18. Retrieved 2020-05-11. 
  11. "Niger Delta: Pipelines Attackers Are Experts -Buhari". CSO Maritime Alliance. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  12. Reporter, T. N. C. (30 November 2016). "Niger Delta: Insiders blowing up pipelines –Buhari". The News Chronicle. Archived from the original on 1 December 2016. Retrieved 11 May 2020. 
  13. Opejobi, Seun (29 November 2016). "Niger Delta militants are not ordinary Nigerians - Buhari". Daily Post Nigeria. 
  14. "Professional Engineers Blowing Up Pipelines, Says Buhari". Concise News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 30 November 2016. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  15. "People bombing pipelines not ordinary Nigerians, says Buhari". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics. 29 November 2016. 
  16. "Ẹda pamosi". guardian.ng. Archived from the original on 2021-11-27. Retrieved 2020-05-11. 
  17. "APWEN honours Engr. Mrs. Joana Olutunmbi Maduka in Lagos". Construction & Engineering Digest (CED) Magazine. 13 May 2019. Archived from the original on 2 March 2021. Retrieved 11 May 2020. 
  18. Amana, Destiny. "The Nigeria Academy of Engineering :: promoting excellence in technology and engineering training and practice to ensure the technological growth and economic development of Nigeria". www.nae.org.ng (in English). [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  19. "Highly skilled engineers responsible for pipelines sabotage — Buhari » Latest News » Tribune Online". Tribune Online. 29 November 2016.