Joe "King" Oliver
(Àtúnjúwe láti Joe Oliver)
Joe "King" Oliver (May 11, 1885 – April 10, 1938) je afon fere kornet jazz ati olori egbeonilu. Agaga o se pataki fun iru ona to fin fan fere, nipa kikoko lo idake. Bakanna bi alasopo orin to se pataki, o fowoko opo awon orin ti a si ngbo loni, bi "Dippermouth Blues", "Sweet Like This", "Canal Street Blues", ati "Doctor Jazz". O lo ko Louis Armstrong ni orin jazz. Ipa re ga to be to ti Armstrong fi so pe, "ti ko ba se fun Joe Oliver, jazz ko ni ri bo se ri loni".[1]
Joe "King" Oliver | |
---|---|
Joseph Oliver, about 1915 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Joseph Nathan Oliver [1] |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | King Oliver |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Aben, Louisiana, USA |
Irú orin | Jazz Dixieland |
Occupation(s) | bandleader |
Instruments | cornet |
Associated acts | Louis Armstrong Johnny Dodds |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Satchmo - My Life in New Orleans"