Johannes ǃGawaxab jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀ ède Namibia tí a yàn gẹ́gẹ́ bi gómìnà ilé ifowópamọ́ Namibia, ilé ifowópamọ́ àgbà orílẹ̀ ède náà, a yàn án sípò yìí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹrin ọdún 2020. Ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹfà ọdún 2020.[1]

Johannes ǃGawaxab
Ọjọ́ìbí1956 (ọmọ ọdún 67–68)
South West Africa (now Namibia)
Orílẹ̀-èdèNamibian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNamibian citizenship
Ẹ̀kọ́University of South Africa
(Bachelor of Arts)
(Master of Business Leadership)
Kingston Business School
(Master of Arts)
Iṣẹ́Businessman, central bank governor
TitleGovernor of the Bank of Namibia

Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

A bí ǃGawaxab sí South West Africa, ó sì kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti Sẹ́kọ́ndírì rẹ̀ níbẹ̀. Ó gba àmì ẹyẹ Bachelor nínú ìmọ̀ Arts ní Yunifásítì South Africa (UNISA), ní 1989. Ó te ẹ̀kọ́ rẹ̀ sí iwájú láti gba àmì ẹyẹ Master of Business Leadership (MBL). Ní ọdún 2007, ó lọ sí Harvard Business School, láti kà nípa ìmọ̀ Advanced Management Program.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Lazarus Amukeshe (3 June 2020). "ǃGawaxab assumes central bank job". The Namibian. Windhoek. p. 12. Archived from the original on 3 June 2020. Retrieved 5 June 2020. 
  2. Khomas Archives (2017). "On the spot: ǃGawaxab: His career and verdict on Geingob leadership: Interview With Toivo Ndjebela". Windhoek: New Era Live Namibia. Retrieved 5 June 2020.