Johannes Heesters
Johannes Heesters (ojoibi December 5, 1903) je osere, akorin, ati onifaaji ara Hollandi .
Johannes Heesters | |
---|---|
Heesters in March 2006 | |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kejìlá 1903 Amersfoort, Netherlands |
Ìgbà iṣẹ́ | 1917–present |
Net worth | $65,000,000 |
Olólùfẹ́ | Simone Rethel (1991) |
Website | www.johannes-heesters.de |
Notes | |
Won 19 Bambi-awards |
O ti sise fun odun 91, be sini o sise nibi ti won ti unso ede Jemani. Titi to fi di April 2011, Heesters ni eni agbalagba julo to un sise ninu faaji. Awon kan ko bi fe feran Heesters nitoripe o korin fun Adolf Hitler nigba kan ri.[1]
Heesters segbeyawo ni emaji: lati 1930-1985 o fe osere ara Belgiom Louise Ghijs (1906) ati lati 1991-doni o fe Simone Rethel. Heesters ni omobinrin meji latodo iyawo re akoko ati awon omoomo marun, omoomo-unla mokanla, omoomo-unla-unla medogbon ati omoomokunrin-unla-unla-unla kan ni titi 2011.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Ellicott, Claire (February 18, 2008). "Anger at concert by Hitler singer, 104". The Independent. Retrieved 2008-07-28. Check date values in:
|date=
(help)