Johannes Kepler (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈkɛplɐ]; December 27, 1571 – November 15, 1630) je ara Jemani onimo mathimatiki, atorawo ati aworawo, ati eni orundun 17k pataki ninu ijidide sayensi. O gbajumo fun awon ofin igbera planeti to ni oruko re, ti awon atorawo ojowaju seloroami, ti won da le ori awon iwe re Astronomia nova, Harmonices Mundi, ati Epitome of Copernican Astronomy. Awon ise inu awon iwe yi na tun ni won je ipilese fun ero ifamora alagbalaaye ti Isaac Newton.

Johannes Kepler
A 1610 portrait of Johannes Kepler by an unknown artist
Ìbí(1571-12-27)Oṣù Kejìlá 27, 1571
Weil der Stadt near Stuttgart, Jẹ́mánì
AláìsíNovember 15, 1630(1630-11-15) (ọmọ ọdún 58)
Regensburg, Bavaria, Jẹ́mánì
IbùgbéWürttemberg; Styria; Bohemia; Upper Austria
PápáAstronomy, astrology, mathematics and natural philosophy
Ilé-ẹ̀kọ́Yunifásítì ìlú Linz
Ibi ẹ̀kọ́Yunifásítì ìlú Tübingen
Ó gbajúmọ̀ fúnKepler's laws of planetary motion
Kepler conjecture
Religious stanceLutheran
Signature