John Augustus Otunba Payne
Àwọn Lọ́ọ́yà àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Yorùbá. A kọ ọdún tí wọ́n di looya sí òkè orúkọ wọn
Christopher Alexander Sapara Williams
àtúnṣeO di looya ni 1880
Christopher Alexander Sapará Williams
Òun ni ọmọ Nàìjíríà tí ó kọ́kọ́ di Lọ́ọ́yà
Rotimi Olusola Alade
àtúnṣeO di loya ni 1892
John Augustus Otunba Payne
àtúnṣeO di looya ni 1900
E.J. Alexander Taylor
àtúnṣeO di looya ni 1905
John Akinola Otunba Payne
àtúnṣeO di looya ni 1909
Sir Adeyemo Alakija
àtúnṣeO di looya ni 1910
Olayinka Alakija
àtúnṣeWon di looya ni 1913 Ọláyímíká Alákijà
E.A. Franklin
àtúnṣeWon di looya n 1921 E. A Franklin
Adedapo Kayode
àtúnṣeWon di looya ni 1922
Ayodele Williams
àtúnṣeWon di looya ni 1923
[Ayọ̀délé Williams ]]
C.A. Harrison Obafemi
àtúnṣeWon di looya ni 1924
Rufus Adékúnlé Wright
F.O. Lucas
àtúnṣeWon di looya ni 1925
J. Omoniyi Coker
àtúnṣeWon di looya ni 1926
T.Ekundayo Kusimo Sorinola
àtúnṣeWon di looya ni 1927
Samuel Ayodele Thomas
àtúnṣeWon di looya ni 1928
Omosanya Adefolu
àtúnṣeWon di looya ni 1929
Abiola Akinwumi
àtúnṣeO di looya ni 1930
Ogunyemi Ebikunle Ajose
àtúnṣeO di looya ni 1931
O di looya ni 1933
O di looya ni 1934
O di looya ni 1935
O di looya ni 1936
Won di looya ni 1940
Won di looya ni 1941
Won di looya ni 1942
[[Ọdúnbákú ]]
O di looya ni 1944
Won di looya ni 1946
Won di looya ni 1947
Won di looya ni 1948
[O. Akínkúgbé ]]
Won di looya ni 1949
Won di looya ni 1950
A.G.O. Agbaje
àtúnṣeWon di looya ni 1952
O. Ajose-Adeogun
àtúnṣeWon di looya ni 1953
[Adéníran Ògúnsànyà ]]
[A.R. Bákàrè]]
O.B. Akin Olugbade
àtúnṣeWon di looya ni 1954
[Kẹ́hìndé Ṣófọlá ]]
B.O. Babalakin
àtúnṣeWon di looya ni 1959
Looya akoko ni ile Naijiria
àtúnṣeLọ́yà àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà ni Williams Alexander Sapara Williams. Ó di agbẹjọ́rò ní odún 1880.
Magistrate akoko ni ile Naijiria
àtúnṣeỌmọ Yorùbá nì Májísíréètì kìíní ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà ni Sir Olumuyiwa Jibalaru. Ọdún 1938 ni ó di Majísíréètì yìí.
High Court Judge akoko ni ile Naijiria
àtúnṣeSir Olumuyiwa Jibalaru ni ọmọ Nàìjíríà kìíní tí yoo di adájọ́ ilé-ẹjọ́ kóòtù gíga (High Court of Judge).
Chief Justice akoko ni ile Naijiria
àtúnṣeỌmọ Yorùbá ni Ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ tí yóò di ‘Chief Justice’ ilẹ̀ Nàìjíríà ni Sir Adétòkunbọ̀ Adémọ́lá. Ọmọ Yorùbá ni Ọmọ-ọba Abẹ́òkúta ni.
Senior Advocate of Nigeria (SAN) akoko ni ile Naijiria
àtúnṣeLọ́yà tí ó kọ́kọ́ gba ‘Senior Advocate of Nàìjíríà ‘Chief F.R.A. Williams. Ọmọ Yorùbá ni.
Looya obinrin akoko ni ile Naijiria
àtúnṣeLọ́yà obìnrìn àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tí yóò di adájọ́ ilé ẹjọ́ àgbà (High Court Judge) ní ilẹ̀ Nàìjíríà ni Mrs Modupẹ Ọmọ-Ẹboh tí ó jẹ́ ọmọ Akingbẹhin. Ọmọ Yorùbá ni.
High Court Judge obinrin akoko ni ile Naijiria
àtúnṣeLọ́yà obìnrìn àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tí yóò di adájọ́ ilé ẹjọ́ àgbà (High Court Judge) ní ilẹ̀ Nàìjíríà ni Mrs Modupẹ Ọmọ-Ẹboh tí ó jẹ́ ọmọ Akingbẹhin. Ọmọ Yorùbá ni.
link title Archived 2007-08-07 at the Wayback Machine.