John Cabess
John Cabess (tí àwọn míràn ma ń kó bi John Kabes tàbí John Cabes) (c. 1640s – 1722) jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀ èdè Áfíríkà tí ó gbajúmọ̀ nígbà ayé rẹ̀, ìlú Komenda, ara àwọn ìlú ìjọba Eguafo, ni ó ti ṣòwò. Ó jẹ́ ọ̀rẹ́ orílẹ̀ èdè Britain, ó sì ń ta ọjà fún ilé iṣẹ́ Royal African Company. Gẹ́gẹ́ bi oníṣòwò, ó gbajúmọ̀ ní ìlú Komenda ní àwọn ọdún 1700s, ó kó ipa gbòógì ní ogun Komenda, ìdìde ìjọba Ashanti, ìtàn kálẹ̀ ìjọba Britain ní ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà, àti Atlantic slave trade. Ó fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 1722.
John Cabess | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1640s tàbí 1650s |
Aláìsí | 1722 Komenda |
Orúkọ míràn | John Kabes or John Cabes |
Iṣẹ́ | Prominent merchant in Komenda |