John Couch Adams

John Couch Adams
Ìbí (1819-06-15)15 Oṣù Kẹfà 1819
Laneast, Launceston, Cornwall
Aláìsí 21 January 1892(1892-01-21) (ọmọ ọdún 72)
Cambridge Observatory, Cambridgeshire, England
Ọmọ orílẹ̀-èdè British
Ẹ̀yà British
Ibi ẹ̀kọ́ University of Cambridge
Academic advisors John Hymers

Wọ́n bí Adams ní 1819. Ó kú ní 1892. Ọmọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ni. Onímọ̀ ìṣirò (Mathematics) ni. Astronomer sì ni pẹ̀lú. Òun àti Leverrier, astronomer ọmọ ilẹ̀ Faransé kan ni wọ́n jọ gba ogo ṣíṣe àwárí Neptune ní 1846. Òtọ̀ọ̀tọ̀ ni wọ́n ṣe iṣẹ́ tí wọ́n gba ògo rẹ̀ yìí.