John Dramani Mahama
John Dramani Mahama ( /məˈhɑːmə/; ojoibi 29 November 1958) je Aare ile Ghana ati Igbakeji-Aare orile-ede Ghana tele. O je didiboyan ni idiboyan odun 2008. Teletele o ti je omo Ile-igbimo asofin fun Bole-Bamboi ati omo Ile-igbimo asofin Gbogbo Afrika lati Ghana. O ti je Alakoso Eto Ibanisoro labe ijoba Aare Jerry Rawlings.[1]
John Dramani Mahama | |
---|---|
Ààrẹ ilẹ̀ Ghánà | |
In office 24 July 2012 – 7 January 2017 | |
Vice President | Kwesi Amissah-Arthur |
Asíwájú | John Atta Mills |
Arọ́pò | Nana Akufo-Addo |
Igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Ghánà | |
In office 7 January 2009 – 24 July 2012 | |
Ààrẹ | John Atta Mills |
Asíwájú | Aliu Mahama |
Arọ́pò | Kwesi Amissah-Arthur |
Minister of Communications | |
In office November 1998 – 7 January 2001 | |
Ààrẹ | Jerry John Rawlings |
Asíwájú | Ekwow Spio-Garbrah |
Arọ́pò | Felix Owusu-Adjapong |
Deputy Minister of Communications | |
In office April 1997 – November 1998 | |
Ààrẹ | Jerry John Rawlings |
Member of Parliament for Bole | |
In office 7 January 1997 – 7 January 2009 | |
Asíwájú | Mahama Jeduah |
Arọ́pò | Joseph Akati Saaka |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kọkànlá 1958 Damongo, Ghana |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | National Democratic Congress |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Lordina Mahama |
Residence | Osu Castle |
Alma mater |
|
Occupation | Historian, Communications Specialist, Writer |
Positions |
|
Signature | Fáìlì:John Dramani Mahama Signature.png |
Website | Presidency website |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Linda Akrasi Kotey, "Fireworks in Parliament", Ghanaian Chronicle (allAfrica.com), August 12, 2008.