John Jea

Akéwì ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

John Jea (1773 – lẹ́yìn 1817) jẹ́ ònkọ̀wé, oníwàásù àti awakọ̀ ojú omi ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà mọ́ Áfíríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ìwé rẹ̀ tí ó kọ ní ọdún 1811 The Life, History, and Unparalleled Sufferings of John Jea, the African Preacher. Jea di ẹrú láti ìgbà tí ó sì jẹ́ èwe, lẹ́yìn ìgbà tí ó sì gbòminira ní 1790s, ó bẹ̀rẹ̀ sí ń rìrìn àjò àti wàásù káàkiri.

John Jea
Ọjọ́ìbíc. 1773
Akwa Akpa
Aláìsíunknown
Iṣẹ́
  • Farmer
  • sailor
  • preacher
Notable workThe Life, History, and Unparalleled Sufferings of John Jea, the African Preacher. (1811)
Parents
  • Hambleton Robert Jea (father)
  • Margaret Jea (mother)

Ìpìlẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

Díè ni a mọ̀ nípa ìpìlẹ̀ John Jea yàtò sí òun tí ó kọ nínú ìwé rẹ̀, The Life, History, and Unparalleled Sufferings of John Jea, the African Preacher (1811).

Jea sọ pé wọ́n bi ohun ní Africa ní ọdún 1773 lẹ́gbẹ̀ẹ́ CalabarBight of Biafra,[1] àti pé àwọn akónilẹ́rú jí òun, àwọn òbí òun, Hambleton Robert Jea àti Margaret Jea, àti àwọn ẹbí òun gbé, wọ́n sì ta àwọn fún ẹrú sí New York City, ìṣẹ̀lẹ̀ sí ṣẹ̀ nígbà tí ó sì jẹ́ ọmọ ọdún méjì àti àbọ̀.

Ìdílé Dutch kan, Oliver and Angelika Triebuen, ra Jea. Àwọn olówó rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìjọ Conservative Dutch Reform, tí ó lòdì sí yíyí ẹrú sí ẹ̀sìn Krìtẹ́nì.[2][3] Àwọn olówó rẹ̀ ma ń lọ sí ilé ìjọsìn láti ba wí ṣùgbọ́n Jea di Krìstẹ́nì, a sì ṣe ìrìbọmi fun ní 1780s.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Chambers, Douglas B. (2005). Murder at Montpelier, p. 185.
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :3
  3. Pierce, Yolanda (2005). Hell Without Fires: Slavery, Christianity, and the Antebellum Spiritual Narrative.. University Press of Florida. ISBN 978-0-8130-7217-3. OCLC 1266896138. http://worldcat.org/oclc/1266896138. 
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0