John Madaki

Olóṣèlú

John Madaki jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Katsina nígbà kan rí. A yàn án sípò ní oṣù Kejìlá ọdún 1989 lásìkò ìjọba ológun tí Ààrẹ Ibrahim Babangida. Saidu Barda ló jẹ́ lẹ́yìn rẹ̀ lásìkò ìjọba alágbádá ni oṣù kìíní ọdún 1992.[1][2]

John Yahaya Madaki
Governor of Katsina State
In office
December 1989 – 2 January 1992
AsíwájúLawrence Onoja
Arọ́pòSaidu Barda
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíGurara LGA, Niger State, Nigeria
Aláìsí8 January 2018

Àwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. globalsentinel (2018-01-10). "Niger State mourns Colonel John Madaki rtd". Global Sentinel. Retrieved 2019-12-26. 
  2. "John Madaki (1947-2018) – a tribute". The Sun Nigeria. 2018-02-01. Retrieved 2019-12-26.