John Pepper Clark
John Pepper Clark-Bekederemo (ojoibi April 6, 1935 tosi ku ni ọjọ mẹtala óṣu October ọdun 2020) je olukowe omo ile Naijiria. Arakunrin naa ni órukọ rẹ ma njade nigba toba kọ iwè gẹgẹbi J.P. Clark ati John Pepper Clark[1][2].
John Pepper Clark |
---|
J. P. Clark | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | John Pepper Clark-Bekederemo 6 Oṣù Kẹrin 1935 Kiagbodo, Delta, Nigeria |
Aláìsí | 13 October 2020 | (ọmọ ọdún 85)
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | John Pepper Clark |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Ibadan |
Iṣẹ́ | Poet, playwright |
Notable work | A Decade of Tongues |
Awards | Nigerian National Order of Merit Award |
Igbesi Ayè Arakunrin naa
àtúnṣeJohn ni a bisi Kiagbodo,ilú naigiria fun Baba rẹ to jẹ ọmọ ilè Ijaw ati Iya rẹ to jẹ ọmọ ilẹ Urhobo. Nigba ti arakunrin naa jade lati ilè iwè giga ti Ibadan ni ó ṣiṣẹ gẹ̀gẹbi Officer ti Information ni ministry ti information ati research fellow ni Institute ti imọ ẹkọ ilẹ Africa ni ilè iwè giga ti Ibadan[3][4].
Ni ọdun 1982, John ati Iyawó rẹ Ẹbun Odutola (Professor ati óludari tẹlẹ ri) da theatre ti PEC Repertory silẹ ni ilú eko[5].
Clark ku si ilè iwosan to wa ni eko ni ọjọ kẹkatala óṣu October ni ọdun 2020[6].
Ẹkọ
àtúnṣeClark lọsi ilè iwè Native Authority ni Okrika ni ijọba ibilẹ ti Burutu, ilè iwè ti Ijọba ni Ughelli lẹyin ló tẹsiwaju lọsi ilè iwè giga ti Ilú Ibadan lati kẹẹkọ lọri imọ ede gẹẹsi. Arakunrin naa fun aimoyè ọdun lóti jẹ professor ti èèdè gẹẹsi ni ilè iwè giga ti Eko to si fẹyinti ni ọdun 1980. Clark tigba ipó professor ni ilè iwè giga ti Yale ati Wesleyan ni ilú United States[7][8].
Ami Ẹyẹ ati Idanilọla
àtúnṣeClark gba Ami Ẹyẹ ti National Order of merit ti ilẹ naigiria lati ọdọ ilè iwè giga ti Howard lóri iwè rẹ "The ozidi Saga ati Akójọpọ Ere ati Ewi lati ọdun 1958-1988[9].
Ni ọjọ kẹfa, óṣu December ni ọdun 2011 ni ayẹ Ayè Professor John Pepper Clark pẹlú ayẹyẹ to waye ni Ikoyi[10]. Ni ọdun 2015 ni Awọn ọdọ ólukọwè ti ilẹ naigiria labẹ akoso Wole Adedoyin da ẹgbẹ JP clark ti Literay lati igbè iṣẹ Clark larugẹ[11][12].
Itokasi
àtúnṣe- ↑ https://www.vanguardngr.com/2011/12/jp-clark-the-saga-of-son-of-kiagbodo/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-11-26. Retrieved 2022-11-26.
- ↑ https://www.literatureworms.com/2012/08/john-pepper-clark-bekederemo.html?m=1#
- ↑ https://www.manpower.com.ng/people/15916/john-pepper-clark-bekederemo
- ↑ https://www.premiumtimesng.com/news/more-news/420465-updated-foremost-poet-j-p-clark-is-dead.html
- ↑ https://www.bbc.com/pidgin/tori-54528108
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-11-26. Retrieved 2022-11-26.
- ↑ https://www.britannica.com/topic/Ijo
- ↑ https://web.archive.org/web/20111003194219/http://www.africansuccess.org/visuFiche.php?id=790&lang=en
- ↑ https://www.vanguardngr.com/2011/12/a-voyage-around-j-p-clark/
- ↑ https://www.thenigerianvoice.com/news/292775/synw-mourns-prof-jp-clark-set-to-promote-his-life-and-wor.html
- ↑ http://jpclarklietrarysociety.blogspot.com/2015/10/jp-clak-literary-society.html?m=1