Johnson Toribiong (ojoibi 22 Osu Keje, 1946) je omo orile-ede Palau agbejoro ati oloselu to je Aare ile Palau lowolowo, leyin to bori ninu idiboyan aare Osu Kokanla 2008.[1] O bo si ori aga ni ojo 15 Osu Kinni, 2009.

Johnson Toribiong
Aare ile Palau
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
January 15, 2009
Vice PresidentKerai Mariur
AsíwájúTommy Remengesau
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Keje 1946 (1946-07-22) (ọmọ ọdún 78)
Airai, Palau
(Àwọn) olólùfẹ́Valeria Toribiong