Jónà Jang
Olóṣèlú naijiriya
(Àtúnjúwe láti Jonah David Jang)
Jonah David Jang je omo ologun toti feyinti ati oloselu omo ile Naijiria, ohun ni Gomina Ipinle Plateau lati odun 2007. Nigba ijoba ologun Ogagun Ibrahim Babangida o di Gomina awon Ipinle Benue ati Gongola.
Jonah David Jang | |
---|---|
Executive Governor of Plateau State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2007 | |
Asíwájú | Michael Botmang |
Military Governor of Gongola State | |
In office August 1986 – December 1987 | |
Asíwájú | Yohanna Madaki |
Arọ́pò | Isah Mohammed |
Military Governor of Benue State | |
In office August 1985 – August 1986 | |
Asíwájú | John Atom Kpera |
Arọ́pò | Yohanna Madaki |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kẹta 1944 Du, Jos South LGA, Plateau State, Nigeria |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |