Jones Ọladẹhinde Arọgbọfa (Tí a bí ní ọjọ́ kẹwa oṣù kọkanla ọdún 1952, 10 Oṣù Kejì 2024) wá láti ìjọba Ìbílẹ̀ Akòko tí ó wà ní guusu ìwọ oorun ní Ipinle Ondo. Arọgbọfa jẹ́ ọ̀gágun tí ó ti fẹ̀hìntì nínú iṣẹ́ ológun.[1]

Ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Arogbofa gba oyè Diploma nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìmọ̀ ẹ̀rọ Rochester Institute ní ìlú America, Ó tún gba oyè àkọ́kọ́ ti Yunifasiti nínú ìmọ̀ ẹ̀ro àti oyè ẹlẹ́ẹ̀kejì ti Yunifasiti nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ bakana láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifasiti ti Alabama ní ìlú America.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Jonathan appoints Brigadier-General Jones Oladehinde Arogbofa as new Chief Of Staff". LATEST NIGERIAN NEWS BREAKING HEADLINES NEWSPAPERS. 2014-02-18. Retrieved 2020-03-10. 
  2. "BREAKING: Jonathan appoints retired General Arogbofa as new Chief of Staff". Premium Times Nigeria. 2014-02-18. Retrieved 2020-03-10.