Jonis Bascir
Jonis Bascir tí wọn bí ní ọjọ́ kẹtadínlógún oṣù Kẹsàn-án ọdún 1960, jẹ́ òṣeré àti àkòrin tí ọmọ orílẹ̀ ède Somalia àti Italy.
Jonis Bascir | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kẹ̀sán 1960 Rome, Italy |
Iṣẹ́ | actor, musician |
Ìgbà iṣẹ́ | 1990s–present |
Olólùfẹ́ | Nicoletta |
Parent(s) | Haji Bashir Ismail Yusuf |
Website | jonis.it |
Nípa ayé rẹ̀
àtúnṣeJonis jẹ́ ọmọ Muheddin Hagi Bascir, a sì bi ní ìlú Rómù ní ọdún 1960.[1][2] Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀ ède Somalia, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀ ède Italy.[1] Ó jẹ́ ọmọ-ọmọ Haji Bashir Ismail Yusuf, ààrẹ Somalia àkọ́kọ́.
Iṣẹ́ẹ rẹ̀
àtúnṣeỌ̀pọ̀ mo Jonis fún ipa rẹ̀ nínú eré Un medico in famiglia (1998–2008), ọkàn lára àwọn eré oníṣe Rai 1.[1] Ara àwọn eré míràn tí ó ṣe ni The Stone Merchant (2006), Anita Garibaldi (2012) àti Regalo a sorpresa (2013).[5]
Òun ni agbenusọ̀rọ̀ fún Kosè coffee.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 "Introduzione Agli Studi Postcoloniali" (PDF). Wuming Foundation. Retrieved 3 February 2014.
- ↑ "Bambola Ramona ce la fa". TVBlog. Retrieved 3 February 2014.
- ↑ "Anche Katia Pedrotti e Ascanio Pacelli alla premiere di 'Basilicata Coast to Coast', opera prima di Rocco Papaleo". Gossip.it. Archived from the original on 24 September 2015. Retrieved 26 February 2014.
- ↑ "Alessandra Mastronardi, Randi Ingerman e Max Parodi sul red carpet". Gossip.it. Archived from the original on 24 September 2015. Retrieved 26 February 2014.
- ↑ "Jonis Bashir". CinemaRx. Retrieved 26 February 2014.